Tag: Àṣà Yorùbá
-
A ku Ose Sango!
Owonrin Odi I II II II II I I I Owonrin sindin sapere Adifafun Bata abufun Sango nijo won torun bowaye ebo won ni kiwon ose awon mejeji gbebo won sisebo Bata ni owonrin sindin sapere Sango ani okuu temi iyi kotan lara awon mejeji aye koni gba iyi ara emin ateyin akuojumo Sango yobawa…
-
Ori Eni Lawure Eni O – Iyalorisa Omitonade Ifawemimo
Ori Eni Lawure Eni O Ori Eni Lawure Eni Mo ji lowuro mo dewo mori O Ori Eni Lawure Eni… Ki Ori wa ma sowa nu ooo… Ase Ire O! Translation One’s Spiritual/Inner head is his/her super spell(2ce) I woke up in the morning and held my head One’s Spiritual/Inner head is his/her super spell…
-
Owe ati Ibeere Toni – 05.08.2016
– Dabimoseda Alaisan toni ohun o je eyin(egg) ejo(snake) Ibeere Toni -nje IFE otito siwa bi tati jo mo bi?
-
“B’éni l’ówó bí ò n’íwà, owó olówó ni
B’éni l’áya bí ò n’íwà, aya aláya ni B’éni bí’mo bí ò n’íwà, omo olómo ni If one has money but lack character, it’s someone else money If one has wife but lack character, it’s someone else wife If one has children but lack character, they belong to someone else.” Iwa is the ultimate weapon…
-
Odu Ifa Irosun Afin/ofun
| | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin tu ku isimi opin ose, eledumare yio rojo ibunkun sinu aye wa loni o ase. Odu ifa IROSUN AFIN/OFUN lo gate laaro yi, ifa yi fore Omo aridunu fun akapo ti…
-
Ounje Emi Fun T’ooro Yii – 29.07.2016
HUN !!! Otito wa da bi Akisa Elegbin ni niwaju Oluwa … WOO ORE WA !! Bawo lo se roo pe o mo (mi) to… Nje iwo ri ara re gege bi Ododo loju gbogbo aye ? Se iwa re lo dara julo ti o n ri ara re gege bi …
-
Ogbon O Di Igi A Fi Okun(Rope) …
Ojulu, ti opo-eniyan bama wi won a ni ogbon o di igi a fi okun(rope) won a tun ni kosi abuja(short-cut) lorun ope, sugbon ogbon di igi fun eni ti eledua ba gbon, be sini abuja ‘be lorun ope ti olohun ba gbe ise ara re de. Olohun obami kuku ‘be bi ti atijo sugbon…
-
Olojo Ibi Ti Oni
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi mama wa Omolola Adex ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Yoruba Atata. Maami Olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu alafia ara ati ibale okan. E o ni ba won na oja warawara…
-
Ire ni mo ko
Ire ni mo ji ri Ire tororo d’ori awa o Ire toorun ogberi o mo o Aase IyaOgbe OmoEdu Yeyelufe Oyewole