Home / Àṣà Oòduà / Ounje Emi Fun T’ooro Yii – 29.07.2016

Ounje Emi Fun T’ooro Yii – 29.07.2016

HUN !!!
‪ Otito‬ wa da bi ‪ ‎Akisa Elegbin‬ ni niwaju
‪ Oluwa‬ …
WOO ORE WA !!
Bawo lo se roo pe o mo (mi) to…
Nje iwo ri ara re gege bi ‪‎Ododo‬ loju
gbogbo aye ?
Se ‪‎iwa‬ re lo dara julo ti o n ri ara re gege bi
‪ Ayanfe‬ Olorun ?
GBOMI DAADAA ORE WA !!
Bi Oluwa ba nse Amiwo Ese ni.
Taa lo le duro niwaju ‪ite Olodumare‬ ?
‪Orun‬ nikan lo mo ‪‎eni‬ ti yoo la
Kosi ‪‎Saka lara da‬ ninu eda niwaju
‪Oledumare
DAKUN ORE WA !!!
Ma ri ‪‎enikan‬ gege bi ‪‎Olori Elese‬
‪Eledua‬ nikan lori Koro koowa..
TORIPE
‪ ‎Eniyan‬ n woju…
‪‎Olorun‬ mi a si maa wo Okan.
A KU OJUMO..
A ku ‪Ojo Isinmi‬ (SUNDAY) Tonii
Opo Alayo iru-e la o dijo maa se loke Eepe.

About ayangalu

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo