Tag: Àṣà Yorùbá
-
Iwure owuro 26.07.2016
*Aje ko ni di ota a mi. *Edumare dakun fidi aje sole nile mi. *Imo ota, imo elenini ko ni se lori mi. *Emi ko ni di eni arisa ati arisunkun. *Edumare fi aso iyi wo mi(Ase). Aare Olasunkanmi Alani Agbasaga
-
Ore yeye Osun!
May we all be blessed today and beyond. Ore yeye Osun! Take it to the river. Ore yeye Osun! – – –
-
Iyawo tagbe wani ojo aiku mati soro, egbo bose wi
Olotu: ekasan ooo eyin ara ile,asiku asiko yin, eledua yowa pelu gbogbo wa o,ase. Iyawo tagbe wani ojo aiku mati soro egbo bose wic….Gbogbo eyin ebi mofe ki e fi ise yin bura fun mi pe ti moba so e ni lemi jade ni ile oko mi,e sini jeki iya oko mi wa gbe ile…
-
Abi e roju aye bi?
Orewa nso fun ara ile wipe ki won Ba oun gbe orin, sugbon won o da loun, lo ba binu lo Si oko o da orin sugbon won o fun lounje, o tun lo si Odo o da orin won o je ko we(bath) beni won o fun ni Omi mu, o wa pada sinu…
-
Ounje emi fun t’ooro yii ( 20 – 07 – 2016 )
HUN !!! # Odo to gbagbe # Orisun … Gbigbe nii gbe … WOO ORE WA !!! Ibi Ipile eda L’orisun won.. Ibi Eniyan ti lalehu ni Ipile re… Eni to bini Orisun eni nii se… Eniyan to wo’ni dagba Ipile eni nii … Eni a dijo Sewe di Agba orisun eni niwon.. GBOMI DAADAA…
-
Iyawo: mi o le gba ki iya oko mi gbe pelu mi lailai.
Olotu:kini ikan tori tofi ni o le gba ki iya gbe pelu re,gbogbo awon eyan loti ba e so,o ko,o loni gbo,won tun gbe e wa sori afefe,agidi yi nan lotun lo.Kini ikan to sele gan. Iyawo:seri olotu,mole gba ki gbogbo eyan wasi ile wa o,amon iya oko mi,mi o le gba o.Ti oko mi…
-
Olojo Ibi Toni
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Alfa Ola Akeem Totofun’un ti won je okan pataki ninu ebi Ooduarere. Olojo ibi oni a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu alafia ara ati ibale okan. Ni oruko Eledumare e o ni ba won na oja…
-
Ojumo Ire
B’ojumo ba mo .. Ooye a la #peregede.. A D’ifa fun Peregede tii se yeye #Ojumo . A KU OJUMO #Ojumo to mowa Lonii. #Ojumo_Ire gbogbo ni yoo je funwa lase Oba mi Oke .
-
Elesin Oyan
Iba Orunmila Bara Agbonniregun; Elesin Oyan; Adagbaa Ojomu; Gbolajoko Omo Ere l’apa; Baba Okinkin ti n m’eyin erin fo; Odudu tii du ori emere ti o je ko fo; Atori eni ti ko sunwon se! Iba Baba o!
-
Oniwowo ado! Baba dakun ma na mi o! Aase!
OBALUAYE!!!!!! OOOOOOO cc- Babalawo Ifakayode Oyedele Osaifa