Category: Metro life
-
Ọjọ́ ìbí ọgọ́ta ọdún, Ogogo.. ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ eré bọ́lùú wáyé
Ọjọ́ ìbí ọgọ́ta ọdún, Ogogo.. ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ eré bọ́lùú wáyé Fẹ́mi Akínṣọlá Ìlúmọ̀ọ́ká òṣèré tíátà Yoruba to tí ta gbòǹgbò káàkiri àgbáyé ni Alhaji Taiwo Hassan tí ọ̀pọ̀ èèyàn mọ̀ sí Ogogo ọmọ kúlódò jẹ́. Nítorí náà kò ya ni lẹ́nu nígbà tí ètò lónírúurú gbode kan fún ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọgọ́ta ọdún tó ṣe. Lára…
-
Agun Baniro So wipe, Ilu Eko ni Olulu Ipinle Abuja Wa
Aara meriri, egbani eleja, arabirin kan ti o un se agun ba ni ro so wipe olulu ipinle Enugu Ni Anambra, ati pe o tun so wipe, olulu ipinle Eko ni ilu Abuja. Eyin je oun ti o bani ninu je wipe akeko gboye ni ile eko giga, kuna lati so idaun si awon ibere…
-
Posita gbigba okore pada Kun ilu Port-Harcourt Egba ni eleja
Posita wagba okore kun igboro ilu Port-Harcourt
-
Iyawo: mi o le gba ki iya oko mi gbe pelu mi lailai.
Olotu:kini ikan tori tofi ni o le gba ki iya gbe pelu re,gbogbo awon eyan loti ba e so,o ko,o loni gbo,won tun gbe e wa sori afefe,agidi yi nan lotun lo.Kini ikan to sele gan. Iyawo:seri olotu,mole gba ki gbogbo eyan wasi ile wa o,amon iya oko mi,mi o le gba o.Ti oko mi…
-
Oro Sunuku – Ore Mi, Iran Kefa .
.( Ni gbongan adulawo ni Yunifasiti Afonja, awon eniyan n wole leni tere, eji tere. Won n gba tikeeti, won si n wole jokoo. Awon ti o fe safihan sinima naa n gunke, won nso. Won nfa waya, won gbaradi. Ori ife kan rore nlo labele lori ero amohundungbemu ti o wa ni gbongan naa.…
-
Olajumoke omo oniburedi
Opolopo ni i pokiki Olajumoke Orisaguna omo oniburedi gege bi oloriire ti Edumare da lola ojiji pelu bo se se alabapada agbaoje ayaworan ati olorin ti n je TY Bello. Laaarin iseju kan, omo oniburedi di orekelewa oba onise oge. Aimoye awon ile ise alaso oge ni won ti bere si sanwo tabua fun un…
-
E pade awon ore yin nibi
Orisiirisii ona ati idi pataki ni awon eniyan fi n yan ore tuntun. Awon kan fe alajoso, awon kan fe alabaro, awon kan si n fe eni ti won yoo jo maa takuroso lasan. Eyiowu ko je, ore dun ti a ba fi ife otito ati ododo ba ara wa lopo. Die lara awon ti…
-
Kini ero yin nipa awon obirin to ga fiofio?
Mo mo wi pe awon obirin maa n fe lati fe awon okunrin to ba ga. Sugbon mi o mo boya bakan naa lori pelu awon okunrin nipa fiferan awon obirin to ga fiofio. Se kii se wi pe giga obirin le mu awon okunrin maa sa fun?