Tag: Àṣà Yorùbá
-
Ewu Gereye – Adeyanju Ahmed Akewi Imoran
Iya nii je ta ni moo ri, Owo tabua nii je mo ba o tan Igba taa ba n wo sokoto penpe Baye ba ko ni lona Won le moju fira bi eni ofo se Boo rokele atata bu Aye kii rini Ojo iku kakun mole Ode o ni saroye Ojo ikun ba jeko lo…
-
Ogulutu Oro Toni – 30.06.2016
Hummmmmm mase afarawe tori ohunti Taiye se tomuje ,kehinde lese koyi lowo.. Beere lowo orire kotolo Pate nibi Oja gbe nta Tori ohun gbogbo lowo ori ni ooo ooo….ire oooo King Ogulutu Oro
-
Ibeere Toni
Nje oda ki Ololufe Meji jo so bi won se gbe igbe aiye won kiwon to pade arawon paapa julo obinrin????
-
Itunmo Ala wipe Olopa mu yin.
Bio Bala alawipe loju orun olopa mue waa bo ninu ewu tio koju dae sungbon ti olopa ba mue tio fi handcuff sie lowo Oranla Kan nbo wa fune AFOWOFA arare ni yio si da oran naa sie Lorun kio yara tete mura kio tera mo adua daada pelu aawe bakan naa ti olopa bamu…
-
Itunmo: Bi e ba Lala wipe loju e’n sa ewa
Bi e ba lala wipe loju orun e’n sa ewa loju orun tabi e won ewa loju orun oore ibukun lopo lopo lati odo olorun oba ni ona owo lanla yio si Kano kio yara tete mura si adua ki olorun oba ofi tete mu alare se Ayandare Olasunkanmi Luqmon Ebedi > ALALILA PELU ITUMORE…
-
Itunmo Ala wipe e ri obo loju orun
Bi o bala ala wipe loju orun wipe e ri awon obo (monkey) meji loju orun tiwon tele ara won alayi dara pupo olorun oba yio seo loore male gbagbe orore yio dayo ona owo yio la fune beesini bio baje eniti onwa iyawo waari ololufe eni bi okanre gidi beesini bio baje obinrin tion…
-
Omo Olojo Ibi toni
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Olori Aina Orosun ti won je okan pataki ninu ebi Omo Yoruba Atata. Olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu alafia ara ati ibale okan. Ni oruko Oluwa e o ni ba won na oja…
-
Kilode ti iku da emi okunrin-osere yi ni egbodo?
ojulu ni otito, ao gbo iru eleyi ri a fi d’eru ba oloro ni sugbon eleyi ko mi ni omi-inu kilo se alfa abdul-lateef titilope ifa-iwa(itakure) ki lo de ti iku da emi okunrin-osere yi ni egbodo? aaaaaaa olohun-oba aseyi o wu nio ooo amosaaa yoruba bo won ni eni to gbe(dig) ile lopa oku…
-
Ifa naa ki bayi wipe
| | | | | | | | | | | | | YORUBA VERSION: Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isimi oni, emin wa yio se pupo re laye o ase. Odu ifa OKANRAN IRORUN lo gate laaro yi, ifa yi fore Omo gidi ati ire irin ajo lo si…