Home / Àṣà Oòduà / Itunmo: Bi e ba Lala wipe loju e’n sa ewa

Itunmo: Bi e ba Lala wipe loju e’n sa ewa

Bi e ba lala wipe loju orun e’n sa ewa loju orun tabi e won
ewa loju orun oore ibukun lopo lopo lati odo olorun oba ni
ona owo lanla yio si Kano kio yara tete mura si adua ki
olorun oba ofi tete mu alare se

 

Ayandare Olasunkanmi Luqmon Ebedi > ALALILA PELU ITUMORE ATI ONA ABAYO LORIE whatssap or Calling 08089038658

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo