Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 68)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

Fi Ti Okunrin Akonimogba(coach) Egbe Agbabolu Lesesita (Leicester-club) yi se arikogbon

orewa! iwo nan ma ro ararepin, fi ti okunrin akonimogba(coach) egbe agbabolu lesesita (Leicester-club) yi se arikogbon, toripe ORI TI YO DE ADE BOTI WU KORI KONI SE ALAIDE, atipe ILE ANU OLOHUN KI SU fun idi-eyi maso ireti nu ...

Read More »

E Ase iwure yi ooo

Huunn Mose kabiyesi fun oba mi. Oba ajidara Oba toje dada owo e lowo. Iyi ti o da no nbe lowo eledumare Mo wa nbe o. Eledumare Jo o ma fiwa dara buruku o. Ma fun wa ni.omo abami eda. Oooo ...

Read More »

Gbolun kan fun baba oni bata yi

Eku dede asiko yi ooooo. E jo eyin omo ilu mi

Read More »

Oruko Kan Fun Iya omode yii ?

Eyin Eniyan mi Eje Kia Rerin die. Oruko kan fun iya omode yii ?

Read More »

Oro ton’lo Lowo bayi: E wo tomato timo ra ni 500 naira

Eku Dede asiko yio eyin eniyan Atata tin GBE inu ilu Yoruba Atata, oro tonlo Lowo bayi ni mo muwa oro elo obe to won gogo yi ma ni mofe kia soro Lorie o. E wo tomato timo ra ni ...

Read More »

Ibeere Toni: 15.05.2016

Nje Iwo leso “FACEBOOK PASSWORD” re fun Ololufere????? Huuum ema paro ooo

Read More »

Arewa Asa Toni: Afeez ati Mide Martinez Abiodun

Ko so’ogun mo bee si ni ko so’ote mo ni igbeyawo eleyi ti o ku die ko dojubole. Oserekunrin Afeez Abiodun “Afeez Owo” ati iyawo re Oserebinrin Mide Martin ni ti mu ife won padabo sipo. Laipe yi ni edeaiyede ...

Read More »

Iwure Owuro: 14-05-2016

E MAA WI TELE MI : ….. *Fitila ogo mi ko ni ku. *Aso iponju ko ni se dede orun mi. *Oluwa ba mi segun ota ile. *Edumare ba mi segun ota ode. *Ina omo ko ni jo mi. *Ina ...

Read More »

Ogulutu Oro Toni: 08.05.2016

Hummm wo oremi banuso mobayan so tori inu jin. # wo Opolopo ore lo nfara han gegebi ota Oplopo ota naa losi nfi ara han gegebi ore….. # nje Otie mo pe opo alangba lo dankun dele ao kuku mo ...

Read More »

Iki’Ni Fun Ayeye Ojo Awon Iya Wa

ORIN : “E bami KIRA fun ‪#‎Mama‬ mi.. ‪#‎Orisa‬ bi #IYA o.. Ko si Laye… …………….. Iya mi.. Abiyamo lojo Ogun le.. Abiyamo Oloja Aran Abiyamo tii fojooumo wa ko le Dara fun Omo… …………………… Ki Emi gbogbo Awon #IYA ...

Read More »