Home / Àṣà Oòduà / Fi Ti Okunrin Akonimogba(coach) Egbe Agbabolu Lesesita (Leicester-club) yi se arikogbon

Fi Ti Okunrin Akonimogba(coach) Egbe Agbabolu Lesesita (Leicester-club) yi se arikogbon

orewa! iwo nan ma ro ararepin, fi ti okunrin
akonimogba(coach) egbe agbabolu lesesita
(Leicester-club) yi se arikogbon, toripe ORI TI YO
DE ADE BOTI WU KORI KONI SE ALAIDE, atipe ILE
ANU OLOHUN KI SU fun idi-eyi maso ireti nu
l’aye BAO KU ISE O TAN

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo