Tag: Àṣà Yorùbá
-
Arewa Asa Toni: Afeez ati Mide Martinez Abiodun
Ko so’ogun mo bee si ni ko so’ote mo ni igbeyawo eleyi ti o ku die ko dojubole. Oserekunrin Afeez Abiodun “Afeez Owo” ati iyawo re Oserebinrin Mide Martin ni ti mu ife won padabo sipo. Laipe yi ni edeaiyede bee sile larin awon ololufe naa ti Afeez owo si ko eru kuro nile fun…
-
Iwure Owuro: 14-05-2016
E MAA WI TELE MI : ….. *Fitila ogo mi ko ni ku. *Aso iponju ko ni se dede orun mi. *Oluwa ba mi segun ota ile. *Edumare ba mi segun ota ode. *Ina omo ko ni jo mi. *Ina Aya/Oko ko ni jo mi. *Oluwa mu mi tayo laarin akegbe e mi(Ase).
-
Ogulutu Oro Toni: 08.05.2016
Hummm wo oremi banuso mobayan so tori inu jin. # wo Opolopo ore lo nfara han gegebi ota Oplopo ota naa losi nfi ara han gegebi ore….. # nje Otie mo pe opo alangba lo dankun dele ao kuku mo eyiti inu nrun Oremi oro aiye gba # ogbon, #imo ati # oye oooo. #…
-
Iki’Ni Fun Ayeye Ojo Awon Iya Wa
ORIN : “E bami KIRA fun #Mama mi.. #Orisa bi #IYA o.. Ko si Laye… …………….. Iya mi.. Abiyamo lojo Ogun le.. Abiyamo Oloja Aran Abiyamo tii fojooumo wa ko le Dara fun Omo… …………………… Ki Emi gbogbo Awon #IYA wa pata o gun.. Ki #Ounje_Omo o ma koro Lenu yin… Ki e ma fi…
-
Iwure Owuro: 08.05.2016
E MAA WI TELE MI : …….. *Oluwa gba eru iya lori mi. *Edumare ma se je ki n seru egbe. *Oluwa taari alaanu si mi. *Edumare fiso re so mi. *Oluwa pase irorun sinu aye mi. *Iku aitojo ko ni pa mi(Ase). ……… E ku ojulona sinima #ORISUN_OLA latowoo King Ogulutu Oro. …………….. E…
-
Sun re o: Francis Aiyegbeni alase ‘D’Rovans Hotel’ ni ibadan
ojuluoooooooo! owe ni oro-aye, A NLO SI OYO O KOJU SI OYO A TUN BO LATI OYO OYO NAN LO TUN KOJU SI. SE BI ILU-GANGAN. iyen nipe ORUN LATI WA ORUN NAN LAO PADA SI. iku pa ABIRI o ti re orun-alakeji sun reeeoooo Francis Aiyegbeni alase D’Rovans Hotel ni ibadan
-
Tani arakunrin-olokada yi jo ?
Kabiesi re Edua! a se otito ni oro awon agba to sope mejimeji ni Eledua da eniyan. OUN TO BA JO(resemble) OUN LA FI WE ARAWON EPO-EPA JO POSI ELIRI OWO-ALABAUN JO HANHAN-OPE. tani arakunrin-olokada yi jo(resemble)?
-
Ogulutu Oro Toni
Igbiyanju loma ngbeni de ipo ola Igbiyanju loma njeki kadara o se # wo Oremi masinmi igbiyanju oo ki o le dele ileri Majeki isoro kisoro kopa okanre da Lori ipinu ayo re Tepa mose re loni Ki osi mo wo owolowo juen yio dara fun oooo. IRE OO OOOO
-
Ojumo Ire ni
Ile to mo wa loni, ka ma subu ka ma feyin owo danu,toripe ojumo ire ni, ka ma ko elenini ka ma ko agbako toripe ojumo ire ni,ori owo Lori wa loni, ESE aje lese wa lonj aji lowuro ati ba eleda soro wipe koni San wa so rere. Oti ribe koyi pada Ase