Tag: Àṣà Yorùbá
-
Esun idigunjale la o fi kan eni to ba gbegidina ti n gbowo odun” Olopaa Ipinle Ogun
Komisanna awon olopaa ipinle Ogun, Ogbeni Abdulmajid Ali ti kede wi pe,ile ise olopaa ipinle Ogun ti wa ni imurasile lati gbogun ti iwa idaran to seese ko suyo lasiko poposinsin odun taa wa yii. Ninu oro Ogbeni Abdulmajid, eleyii to se ni olu ileese olopaa to wa ni Eleweran niluu Abeokuta, ibe lo ti…
-
A se iru eniyan bayii ni Gani Adams, e gbo ohun ti won so nipa re
E ni lati fi eti ara yin gbo ohun ti Omooba Yomi Tejuosho so nipa Oloye Gani Adams. Eniyan ti a n ri lokeere, aimoye nnkan ni e ko mo nipa eni naa.rara.
-
Se oro Buhari ko ta leti awon asofin ni?
Okan ninu awon asofin, Honourable Essien Ekpenyong Ayi (PDP) lati ipinle Cross River n sun ni akoko ti Aare Buhari n ka iwe eto isuna odun 2016 niwaju ile igbimo asofin Abuja.
-
E wo ohun ti oyinbo amunisin se lodun 1908
Awon oyinbo amunisin lati ilu Belgium yegi fun omokunrin, omo odun meje (7) niluu Congo lodun 1908. Ogbeni Femi Fani-Kayode lo se afihan foto yii lori ayelujara. Okunrin naa si tun fi kun un wi pe, ninu awon oyinbo amunisin to daju ju lo, ilu Belgium lakoko, ilu to sikeji ni Jamani.
-
Yunifasiti ijo Mountain of Fire yoo bere eko kiko lojo Monde
Gbogbo eto ti to bayii fun ileewe giga ti ijo Mountain of Fire and Miracles Ministries (MFM) eleyii ti won pe ni Mountain Top University lati bere eko kiko fun awon akekoo lojo Monde ose yii, 21/12/15. Eto ibere eko kiko ifafiti tuntun yii ni yoo bere pelu ayeye igbaniwole awon akekoo eleyii ti yoo…
-
E Sora! FRSC ti kede oju ona to lewu n’Ijebu
Orisun iwe Iroyin: Lati Ọwọ Olayemi Olatilewa Awon eso oju ona ile Nigeria, Federal Road Safety Commission (FRSC), eka ti Ijebu Ode ti kede awon oju ona to lewu ni gbigba fun awon onimoto ni akoko poposinsin odun yii. Oju ona ti won kede re naa ni masose Sagamu si Ore. Paapa ju lo, ogangan…
-
Oselu Kogi: “Idi ti a ko fi yan Faleke ni yii” – Alaga APC
Alaga fun egbe oselu APC lapapo, Oloye John Odigie-Oyegun ti salaye idi pataki ti awon agba egbe naa fi pamopo lati yan Alhaji Yahaya Bello gege bi oludije ti yoo ropo Abubakar Audu, eni to jade laye saaju ki eto idibo naa to kesejari. Ninu oro re, eleyii to se nibi ipade to ni pelu…
-
Nipinle Ondo, eniyan meji koja sorun nibi ija NURTW
O kere tan awon eniyan bi meji ni won gborun lo ni Ikare-Akoko to wa ni ipinle Ondo nigba ti awon eniyan bi mewaa farapa koja bikiafu nibi ija to wayii laaarin awon omo onimoto. Wahala to bere lati nnkan bi ago meje aaro putu Ojobo to koja yii ni awon ganfe kan ti…
-
Emi ati Alao-Akala ti lepo di okan soso- Gomina Ajimobi
*Ajimobi fogbon juko oro si Ladoja Leyin awuyewuye ati awon oro ti n lo nigboro nipa wi pe gomina tele fun ipinle Oyo, Christopher Alao-Akala n mura lati darapo mo egbe APC ti pada jade lenu Akala funra re bayii. Oro yii ni Alao-Akala, eni ti awon kan tun un pe ni Omo Iya Alaro,…
-
“Ko saaye fun Toll-Gate bayii” – Egbe Akoroyin tiluu Eko
E gbe akoroyin, Nigeria Union of Journalists eka ti ilu Eko, ti gbe atejade kan jade eleyii to n ro ijoba apapo lati se atunse si awon oju ona masose wa ki won to ronu a ti da Toll Gate pada si aarin ilu. Nibi ipade eleyii ti egbe naa se to waye l’Ojoru ose…