Tag: Àṣà Yorùbá
-
E ba wa dasi oro yii
Nje ohun to dara wa ninu ki awon okunrin maa na awon iyawo ile won? Kini obirin le se to le mu okunrin siwo soke na won?
-
Foto: Kini obirin le se na ?
Kini obirin le se na, to le mu oko re na bi eleyii pelu oyun ninu? Iru iwa awon odaju okunrin bayii bani lokan je gidi. Sebi o se maa ri lo ni yii?
-
Taye Ogunlaja: Won ti pa oloye omo egbe NURTW tiluu Eko
*Won gun un lobe lorun pa ni Awon olopaa olotelemuye, eka ti ile ise olopaa ti n risi iwa idaran to wa ni Panti, Yaba ti bere ise iwadii to gbepon bayii lati mo odaju eda to seku pa Taye Ogunlaja, oloye NURTW nikete to jade ninu Mosalaasi kan to wa ni agbegbe Abule- Egba…
-
Ile ejo to gaju lo ni yoo pari idaju iku Reverend King
Ile ejo to gaju nile yii ti kede ojo kerindinlogbon osu keji odun ti n bo (26/02/15) gege bi ojo ti igbejo adari ijo Christian Praying Assembly, Reverend Chukwuemeka Ezeugo, ti gbogbo eniyan mo si Reverend King yoo ma waye. Reverend King yii lo pe ejo ko-temi-lorun latari ejo iku ti ile ejo giga ti…
-
Gobe sele lagbo Davido
Orisiirisii ara ni awon omo olorin igbalode maa n da lagbo ere orin. Iru ara bee ni bi ki won bo aso lorun ki won si ju si aarin ero onworan. Awon mii a maa bo alakorun danu soju agbo lati fi ife han. Nigba mii ewewe, won maa da bi oti tabi omi inu…
-
Iriri awon omuti: Ore meji ku, iketa fara pa
Gege bi oro awon Yooba,”eni Sango ba toju re wole, eni naa ko ni ba won bu oba Koso laelae.” Okunrin kan to pe ara re ni Cde Zenzele Nkosi lori FACEBOOK lo salaye ijamba moto to sele si i nipa iwa oti mimu pelu oko wiwa. Okunrin naa se afihan foto oju-apa to gbe…
-
Igba otun ti de: Raji Fasola ti bo soju ise
Minisita fun ina Monamona, Ise Ode, ati Ilegbee, Babatunde Raji Fasola ti kede eto ati awon igbese re akoko eleyii ti o fi ma side ise ilu ti won gbe le e lowo gege bi minisita. Gege bi gomina eleeketala ti o je ni ipinle Eko se safinhan awon eto re, agbejero agba, eni odun…