Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?
Category: Asa
-

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín
A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-an
Bó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà bo
A dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀
Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o se
Ọ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú o
Baba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yè
Nítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nse
Ire oo -
Ní Ojúmọ́ Ọjọ́ Àbámẹ́ta Tòní – #Kojoda #Yoruba #Orisa
Òsùn gbó ríró, kí o má dubúlẹ̀
Òòró gangan laa bósùn
Òsùn dé o Alàwòrò
Ọlọ́run ọba ma jẹ kí gbogbo wa saarẹMo sé ní ìwúre fun orí kọ̀ọ̀kan wa ní ojúmọ́ ọjọ́ Àbámẹ́ta tòní wípé àìsàn kéré tóbi aráyé kò ní fí se wá tọmọ tọmọ tebí tará
Ọlọ́run kò ní jẹ́ ka dùbúlẹ̀ àìsàn tọmọ tọmọ
Gbogbo àìsàn arawa Olódùmarè yoo wòwá sàn
kí ọ̀sẹ̀ yí tó parí -
I’m Not Scared Of Heaven Because It’s My 2nd Home #Spirituality
I am not religious but I am definitely a spiritual person. I have always said that a religion is for people who are scared of ending up in hell. Spirituality is for those who have already been there…#Proudly Olorisa# #Orisa Forever# #Guardian Orisa# #Yemoja# #Inner vision# #divineself# #Proudly Traditionalist#
Iyalorisa Omitonade Ifawemimo

