Òsùn gbó ríró, kí o má dubúlẹ̀Òòró gangan laa bósùnÒsùn dé o Alàwòrò Ọlọ́run ọba ma jẹ kí gbogbo wa saarẹ Mo sé ní ìwúre fun orí kọ̀ọ̀kan wa ní ojúmọ́ ọjọ́ Àbámẹ́ta tòní wípé àìsàn kéré tóbi aráyé kò ní fí se wá tọmọ tọmọ tebí taráỌlọ́run kò ní jẹ́ ka dùbúlẹ̀ àìsàn tọmọ tọmọ Gbogbo àìsàn arawa Olódùmarè yoo wòwá sàn kí ọ̀sẹ̀ yí tó parí
Read More »Best Reviews
Apoti Yiyi
Aarin Buzi
😳 Mercy Johnson Kìlọ̀ Gidi: “Ọ̀rọ̀ Ọkọ àti Aya, Ẹ Jẹ́ Kí Wọ́n Yanjú Rẹ̀ Fúnra Wọn!”
“Ọ̀rọ̀ ọkọ àti aya tàbí ohunkóhun tó bá kan ìfẹ́, ẹ má ṣe dá sí i, ẹ má ṣe gbìmọ̀, ẹ má sì ṣe ran wọn lọ́wọ́. Wọ́n ti lò mí láti yanju ọ̀rọ̀ wọn.” Mercy Johnson, ẹni tí Regina Daniels ń pè ní Iya Isale(Godmother) rẹ̀, ti dá àwọn ènìyàn lójú lórí pẹ̀lú ọ̀rọ̀ yìí tí ó ń tàn káàkiri lórí social media. Àwọn olólùfẹ́ Regina ti ń so ọ̀rọ̀ tí Mercy so yìí pọ̀ mọ́ àwọn ìròyìn àti ...
Read More »
Àṣà Oòduà Àṣà Oòduà