Kò sí ohun ẹlẹ́mìí kankan láyé awo ilé Ayé ni ọ̀run àkọ́kọ́, ohun tí ó so kàrà tí kò sọ̀kalẹ̀, awo òde Ọ̀run ni ó ń pè é, gbogbo rẹ̀ jẹ́ òfìfo lásán, òfo pónbele, láìní ìpìlẹ̀, láìní ẹ̀dá kankan, ...
Read More »Blog Page
Ó San Owó Ilé Ìwé Mi Títí Mo Fi Jáde, Ṣùgbọ́n Mo Fi Májèlé San!
Àti ilé ìwé e gírámà ni èmi àti Kọ́lá ti jọ ń fẹ́ ra wa. Àwọn òbí i mi ò kí ń fẹ́ rí Kọ́lá pẹ̀lú u mi nítorí ààfín ni. Nígbà tí mo fẹ́ wo ile ìwé gíga ni ...
Read More »Iru Ekun: Sunday Igboho ti kéde o!
Sunday Igboho, ti kéde rẹ̀ fún gbogbo ọmọ Yorùbá pé ìforúkọsílẹ̀ láti dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ àbò “Iru Ekun Security Network” jẹ́ ọ̀fẹ́ ti kò sì ní ná kọ́bọ̀ kankan fún ẹnikẹ́ni tó fẹ́ yọ̀ǹda ara rẹ̀ fún àbò ilẹ̀ ...
Read More »Àwọn Ìyàwó Bàbá
Ìyàwó méjì ni bàbá mi fẹ́ àwọn ìyàwó méjèèjì ló sì ti papòdà. Èmi nìkan ni ìyá mi bí fún bàbá mi, mo ní àwọn ọbàkan mẹ́fà.Èmi ni àkọ́bí. L ẹ́yìn Oṣù mẹ́fà ti bàbá a wa kú , àwọn ...
Read More »Mosalasi Fe Di Wiwo Fun ile Adire
Ìbéèrè tóni
Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?
Read More »Ìpínlẹ̀ Eko ní ìfojúsùn ìpè pàjáwìrì ìsẹ́jú márùn-ún péré
Ìpínlẹ̀ Eko ní ìfojúsùn ìpè pàjáwìrì ìsẹ́jú márùn-ún péré Yínká Àlàbí Ile-iṣẹ Aṣẹ ati Iṣakoso Pajawiri ti Ipinle Eko sọ pe awọn ti setan lati dahun si awọn ipe pajawiri ni ipinlẹ Eko laarin isẹju marun-un pere.Olùdarí Àgbà fún ilé-iṣẹ́ ...
Read More »Orí kó Seun Kuti yọ kúrò lọ́wọ́ ikú ní yàrá ìgbàlejò US
Mary Fágbohùn Olórin Afrobeat Seun Kuti ti fi ìrírí ibanuje ọkàn rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà han nígbà tí ọta ibọn kan gúnlẹ̀ lójú fèrèsé yàrá igbalejo rẹ̀. O salaye ibapade to ba ni lẹru naa lori oju-iwe Instagram rẹ, o ...
Read More »Aáyẹ tí ó de bá àṣà
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò ...
Read More »Tírélà jábọ́ láti orí afárá l’Eko, rún Korope méji pa
Tírélà jábọ́ láti orí afárá l’Eko, rún Korope méji pa Fẹ́mi Akínṣọlá Aago mẹ́sàn-án òwúrọ̀ ló ń lọ lu lọjọ Àbámẹ́ta, ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n, oṣù Kerin 2025, tírélà kan fi jábọ́ láti orí afárá Pen Cinema, Agege, l’Ekoo, tó sì run ...
Read More »
Àṣà Oòduà Àṣà Oòduà










