Oko ajagbe eleru leyin kan jabo lati ori afara to wa ni Ojuelegba niluu Eko losan-an oni. Eniyan meji to wa ninu oko ti ajagbe naa jabo le lori fi ile aye sile loju-ese ti isele naa waye nigba ti awon kan fara pa koja bo ti ye.
Tagged with: Wizkid Ojuelegba