Home / Àṣà Oòduà / Igbe aye Oba Lamidi Olayiwola Atanda Adeyemi dun bi oyin

Igbe aye Oba Lamidi Olayiwola Atanda Adeyemi dun bi oyin

Oba_Lamidi_Olayiwola
Laipe yii ni Oba Lamidi Adeyemi, Alaafin Oyo pe eni odun metadinlogorin. E le ka iroyin naa nibi:

Lara awon foto ojo ibi baba mi-in to te wa lowo ni eyi ti baba ya pelu Olori Badirat Adeyemi, olori baba to kere ju lo.

Bi Oosa Oyo tile ti dagbalagba, Olori Badirat, eni to sese wo ile iwe giga Ifafiti lodun yii ko je ki ara baba o darugbo kiakia pelu awon itoju orisiirisii ti n fi n te baba lorun niyewu. Eleyii to si n mu baba dabi omo tuntun jojolo.

Ti won ba ni Oba wo lo jaye ju laye? Walahi, Oba Lamidi ni!

Orisun

About oodua

One comment

  1. Oba Lamidi with his very young child bride.Thats okay I guess cos he’s not from the North of Nig.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo