Olórí ìpínlè télè (former head of state) General Yakubu Gowon lo kí Ààre ti télè Shehu Shagari ní ilé rè ní Sokoto.
Gómìnà Tambuwal sìn-ín lo pèlú Olórí àlùfáà Ìjo Catholic ti Sokoto, Bishop Matthew Hassan kukan àti àwon ènìyàn láti àgbáríjo aládùráà ní orílè èdè Nàìjíríà tí Gowon “Gowon’s NIGERIA PRAYS organization…

Àṣà Oòduà Àṣà Oòduà






