Home / Àṣà Oòduà / Irú kí ni eléyìí báyìí, àfi kí olúwa olódùmarè .

Irú kí ni eléyìí báyìí, àfi kí olúwa olódùmarè .

Nìjíríà àfi kí olórun gbà wá lówó gbogbo hílàhílo tí ó ń selè yí, irú kí leléyìí báyìí .

Eléyìí ló selè ní Oghara. arábìnrin kan ni ó ún gun òkadà lo tí ó sì gbé epo beetíròlù séyìn nígbà tí okò tí a mò sí Lexus jeep, epo beetíròlù yí dànù arábìnrin yí sì jóná di eérú.

Olórun, olódùmarè dárí jìwá ní orílè èdè yí..

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?