Home / Àṣà Oòduà / Tuface àti àwon omo rè okùnrin méjì Nino àti Ziona Idibia ní New York.

Tuface àti àwon omo rè okùnrin méjì Nino àti Ziona Idibia ní New York.

Tuface àti àwon omo rè okùnrin méjì Nino àti Ziona Idibia ní New York.

Gbajúgbajà tí ó tún jé ògbóntarìgì olórin ìgbàlódé ti a mò sí Tuface Idibia tí ó wà ní orílè èdè United State báyìí fún ìrìn àjò rè ni ó ya àwòrán pèlú àwon omo rè okùnrin méjì tí ó jo ó bí ìmumu, Nino àti Ziona tí won jo jáde pò ní ìpínlè New York.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?