Home / Àṣà Oòduà / Gbajúgbajà òsèré Olu Jacob mò wípé àgbàtó omo ni mí báyìí ni Joke Silver se so.

Gbajúgbajà òsèré Olu Jacob mò wípé àgbàtó omo ni mí báyìí ni Joke Silver se so.

Gbajúgbajà òsèré, Joke Silver so wípé nse ni olóògbé E.A Silver àti Dr.Abimbola Silver gba òun tó ni sùgbón nse ni kìí se wípé òun kò mò télè .
Joke Silver so wípé nígbà tí ó yá ni oko òun mò wípé won gba òun tó ni.
Bí ó tilè jé wípé won gba mama tó ni baba kò saláì má n’ífè rè béè.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?