Home / Àṣà Oòduà / Àwon àjo tí ó n mójú tó ètò ìdìbó tí a mò sí INEC ti kéde Gboyega Oyetola gégé bí eni tí ó gbégbà orókè níbi ìdìbò tí won tún dì ní àná.

Àwon àjo tí ó n mójú tó ètò ìdìbó tí a mò sí INEC ti kéde Gboyega Oyetola gégé bí eni tí ó gbégbà orókè níbi ìdìbò tí won tún dì ní àná.

Àwon àjo tí ó n mójú tó ètò ìdìbó tí a mò sí INEC ti kéde Gboyega Oyetola gégé bí eni tí ó gbégbà orókè níbi ìdìbò tí won tún dì ní àná.
Omo egbé oní ìgbálè tí won fà kalè láti lo fún Gómìnà, egbé tí a mò sí APC ti yan Gboyega Oyetola láti lo fún gómìnà ìpínlè Osun.
Àjo tí ó n sètò ìdìbò ti kéde Gboyega Oyetola gégé bí eni tí ó gbégbá orókè níbi idìbò tí won sèsè tún dì tán.
APC rí àwon olùdìbò tí ó tó 255,505, tí àwon PDP sì ní èèyàn tí ó tó 255,023…

About Awo

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo