Home / Àṣà Oòduà / Àwon egbé òkùnkùn Badoo ti pa Ebí tí ó jé méta ní Epe ní ìpínlè Eko .

Àwon egbé òkùnkùn Badoo ti pa Ebí tí ó jé méta ní Epe ní ìpínlè Eko .

Àwon omo egbé òkùnkùn tí pa ebí tí ó jé méta tí won sì fi omo kékeré tí ó fi ara pa sílè ní Epe ní ìpínlè Eko. Won ti pa gbogbo ìdílé kan run sùgbón won fi omo kékeré kan tí ó pa l’ára gan sílè ní Epe ní ìpínlè Eko láìpé yí.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?