NEW! Àǹfààní àgbàyanu fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ pàtàkì wa!Ka siwaju
38°C
16 November 2026
Àṣà Oòduà Iroyin Pajawiri

Akékòó tí ó se dáradára jùlo ní ilé-èkó gíga tí a mò sí ABUAD gba èbùn nlá fúm oríre yí.

  • September 19, 2018
  • 1 min read
  • 2 Views
[addtoany]
Akékòó tí ó se dáradára jùlo ní ilé-èkó gíga tí a mò sí ABUAD gba èbùn nlá fúm oríre yí.

Bí omo eni bá dára kí á wí, Akékòó gboyè ti ìmò tí ó n se ìtòjú ènìyàn tí a mò sí Medical Student, ti gba èbùn pàtàkí tí a mò dí Okò bògìnì àti owó goboi.
Esther Azom ni orúko akékòó yí njé, a gbó wípé okò afé tí won fún náà kojá Mílíónù lónà márún-ún àtiwípé Ooni ti ilè ifè fún arábìnrin náà ni àádótá-lé’rúgba (#250, 000) tí àpapò owó tí ó sì gbà jé (#750, 000).

About Author

Awo