Author: Awo

  • Àwòrán ìsìnkú Odudu Davis, olóòpá tí ìbon àwon olóòpá ojú omi bà tí ó sì kú ní ìpínlè calabar. 

      Ní’sàlé ni àwòrán ìsìnkú olóyè nínú ológun (Corporal)  Odudu Davis tí ìbon pa nígbà tí osù kàrún di ogbòn ní inú odún yìí (30/5/2017)láti owó àwon olóòpá ojú omi (naval officer) nígbà tí àwon olóòpá àti àwon olóòpá ojú omi kolu ara won ní àgó olóòpá  tí ó ń jé Akim (Akim police station)…
  • A kú àyájó odún *Òmìnira* ti *orílè Èdè Nàìjíríà* ?? lónìí ooo.

    A kú àyájó odún *Òmìnira* ti *orílè Èdè Nàìjíríà* ?? lónìí ooo. Èmí wa yóò se púpò rè láyé.
    E jòwó, e má sì gbàgbé láti se *ìwúre* fún orílè èdè *Nàìjíríà* ?? nítorí wí pé *”Ìròrùn igi ni ìròrùn eye”*. Àgbájo owó la fi ñ sòyà, àjèjé owó kan kò gbérù dórí.

    A sì tún kú àmójúbà *osù Òwàwà (October) tuntun*. Osù aláyò ni yóò jé fún wa láse Èdùmàrè. Èmi ò ní dòkú, èyin náà ò ní dòkú, gbogbo wa ni a yóò rí òpin odún yìí láyò àti àlááfíà… *(Ase! )*
    ????????
    *omo oòduà rere ń kì I yín…

  • Ìyàwó mi dára sùgbón kò n’ìfé ìbálòpò léyìn ìgbeyàwó.

    Ìyàwó mi dáa tí mo sì le pè ní aya rere sùgbón kìí gbà kí á bá ara wa lò nígbà tí ó ye, lóòtó aní omo okùnrin pèlú obìnrin. E jò ó kí ni mo le se? Mo ti gbìyànjú àwon nkan tí mò ti kà ní orí èro ayélujàra Kódà a tún jo lo sí ibi àpérò láti le jé kí ó yí padà sùgbón kò yí padà… E jò wó mi ò so eléyìí láti bà á jé sùgbón ònà yí nìkan ni mo gbèrò kí ó yí padà .

    Egbàmí n’ímòràn e jò ó!!!

  • Kílódé tí àwon omoge fi n’ìfé àwon tí ó ti n’íyàwó.

    E jòwó mo fé kí e dá mi lóhùn dáadáa.

    Gbogbo àwon Òré mi tí ó ti n’íyàwó n’ílé ni òpò obìnrin ń súré tè lé, tí ó sì jé wípé àwon àpón bí ti àwa yí obìnrin díè ni ó súré tèle wa, mo ti è fé mò gan. Àti àwon( Òré mi tí ó ti n’íyàwó) jé éri si èyí, wípé àwon omoge ń du àwon tí ó ti n’íyàwó, wón gbàgbó wípé àwon máa ń se ìtójú obìnrin dáadáa, e jòwó Sé òtító ni èyí?

    Obìnrin  Lásán…