Author: Awo
-
Ìyá omo keta gbajúgbajà olórin tí a mò sí Wizkid, tí orúko ìyà omo náà a máa jé Jada Pollock pín àwòrán omo rè, Zion.
Ìyá omo keta gbajúgbajà olórin tí a mò sí Wizkid, tí orúko ìyà omo náà a máa jé Jada Pollock pín àwòrán omo rè, Zion. Alámójútó Olórin àgbáyé, Wizkid tí ó padà di ìyá omo rè, Jada Pollock pín àwòrán omo won tí ó rewà.
-
Linda Ikeji àti omo rè, tí orúko omo náà n jé Jayce Jeremi nínú àwòrán tuntun.
Gbajúgbajà elétíofe tí gbogbo ayé mò sí Linda Ikeji tí ó sèsè bí omo okúnrin rè ní ojó ketàdínlógún osú kesàn-án odún tí a wà yí, pín àwòrán sí orí èro insítágírámù pèlú omo rè, Jayce. Ó ko síbè wípé… “Mo gbàdúrà wípé kí gbogbo obìnrin di abiyamo…kò sí ayo tí ó tó èyí”.
-
Ògúndá Ọ̀wọ́nrín (Ògúndẹ̀rín)
Àtẹ́lẹwọ́ mi ọ̀tún ni mo fi kọ́’fá ń dídá Mo mọ Ifá ń dídá A dífá fún Akítán tíí ṣe ọmọ’yè Oníkàá Àtẹ́lẹwọ́ mi òsì ni mo fi kọ́bò ní gbígbà Mo mọ ìbò ni gbígbà Dífá fá fún Aṣọ̀gbà tíí ṣe ọmọ Ẹkùn ni Ìròkò Kádífá káyẹ̀gẹ̀ – káyẹ̀gẹ̀ Kádífá Dífá fún Òrógbòńdú tíí…
-
Stephanie Hornecker wo aso tí oyàn rè n hàn feere níbè, tí ó sì dàbí egbin nínú è
Stephanie Hornecker wo aso tí oyàn rè n hàn feere níbè, tí ó sì dàbí egbin nínú è. Arewà télè tí ó tún jé òsèré orí ìtàgé sùgbón tí ó ti di Olùwòsàn báyìí, Regina Askia pín àwòrán tí ó rewà ti omo rè tí ó jo ó, omo odún mérìndínlógbòn, orúko omo náà a…
-
Ànto Lecky wo Ejò rògbòdò yíká orún rè
Ará ilé Bbnaija télè tí a mò so Anto ti gbé àrà òtun yo fún àwon olólùfé rè, nígbà tí ó lo sí àgbàlà ejò rògbòdò ní orílè èdè Republic of Benin. Ó ko síbè wípé: ” Ní àgbàlá ejò nlá nígbà tí mo rin ìrìn àjò lo sí Quidah, orílè èdè Benin Republic
-
Yorùbá dún
Hà à à!! Elédùmàrè ìgbà wo l’ènìyàn yόò to bo nínú hílàhílo òde ayé yìí nà? Ki baálé ilé jáde láti òwúrò kùtùkùtù àná kό sí ma b’ojú wéhìn wo, Ǹjé irú ìwà béè daa?? Àmò sà à!! Èyí tà á se sikù, Ohun owό mi ό to, ma fi gogo fà. ‘modé yìí bami…
-
È má jé kì olá èro ayélujára tàn yín je- báyìí ni Joke Silva wí.
Nínú ìfòròwánilénuwò nínú ìwé ìròyìn ti Genevieve Nnaji tí won se fún ognóntàrigì òsèré orí ìtàgé tí a mò sí Joke Silva, ni ó ti gba àwon èèyàn ní ìmòràn kí won má se jé kí ohun tí àwon elégbé òhun máa n pín sí orí ìtàgé tàn wón je, nítorí òpò nínú won ni…
-
Àwòrán Ìlú Abeokuta nígbà tí a wò ó láti orí òkè olúmo (olumo rock).
Òkè olúmo jé òkè kan gbòógì tí a kò le fi owó ró séyìn nínú àwon òkè tí n be ní orílè èdè Nìjíríà, kìí wá se orílè èdè yí nìkan ni a kò tile fi owó ro séyìn bí kò se wípé káàkiri ilè Adúláwò. Orí òkè yí ni àwon kan wà tí won…
-
Àwon àjo tí ó n mójú tó ètò ìdìbó tí a mò sí INEC ti kéde Gboyega Oyetola gégé bí eni tí ó gbégbà orókè níbi ìdìbò tí won tún dì ní àná.
Àwon àjo tí ó n mójú tó ètò ìdìbó tí a mò sí INEC ti kéde Gboyega Oyetola gégé bí eni tí ó gbégbà orókè níbi ìdìbò tí won tún dì ní àná. Omo egbé oní ìgbálè tí won fà kalè láti lo fún Gómìnà, egbé tí a mò sí APC ti yan Gboyega Oyetola…
-
Òrò ìsítí gbó òréëwa?
Òrò ìsítí gbó òréëwa? -O féékú wàákú, Ìwõ ò fèékú wàákú sugbon kini kan lèmi fë kio mø daju, Sé nigba tó o wásí ile-aye sé kii sepé àrà(Wonder) ku mó ë ninu. Àrà tóò gbéwá silé ayé tóò ló, tíò “manifest ninu aye rë tawön eniyan o ” benefit ninu rë, tóo bá kú…