Home / Author Archives: Awo (page 5)

Author Archives: Awo

Oònirìsà sòrò nípa bí àwon èèyàn se n so kiri wípé èjè ni olorì tuntun tè mólè.

Oònirìsà sòrò nípa bí àwon èèyàn se n so kiri wípé èjè ni olorì tuntun tè mólè. Oònirìsà ti jé kí á mò wípé yèyélúwà kò te èjè mólè rárá àti wípé Osùn ni Oluwaseyi Moronke, Yèyélúwà tuntun tè mólè ...

Read More »

Kò kò, ó gbà láti se ètùtù, Moronke Naomi Oluwaseyi gbà láti se òun tótó gégé bí olorì àkókó láàrin àwon olorì pátápátá.

Bí won se ni kó se é ló se é. Bí ó tilè jé wípé àtúnbí nínú Jésú ni, kò kò láti se àwon ohun tí ó tó gégé bí olorì láàfin Oòni ti ilé-ifè. Àwòrán ibi tí ìyàwó ti ...

Read More »

Bí ò bá dùn yóò pé, bí ó bá pé yó dùn; Òònirìsà fé ìyàwó tuntun.

Bí ò bá dùn yóò pé, bí ó bá pé yó dùn; Òònirìsà fé ìyàwó tuntun. Sùúrù tí ó lójó ni Omo Ogunwusi fi se, Aláse èkejì Òrìsà so Naomi Oluwaseyi Silekunola di Olorì láàfin rè. Èyin omo odùduwà e ...

Read More »

Alex Asogwa di onílè púpò ní Omo odún méjìlélógún (22).

Ará ilé Big Brother Naija télè tí a mò sí Alex Asogwa tí ó sèsè towó bo ìwé pèlú ilé-isé tí ó n ta ilè tí ó tún ń ta Ilé, ilé-isé real estate and investment company.Alex Asogwa ti gbe ...

Read More »

KÍ LÓ BÀJẸ́ LÉDÈ WA

Ẹ jẹ́ kí a tibi pẹlẹbẹ mú ọ̀lẹ̀lẹ̀ jẹ. N jẹ́ fífi gẹ̀ẹ́sì kọ́ni lédè Yorùbá le múni yege dáada nínú ẹ̀kọ́ èdè Yorùbá bí? Gẹ́gẹ́ bíi òwe gẹ̀ẹ́sì kan tí ó wí pé, “the best way to understand a ...

Read More »

Odún pé, odún jo, àmòdún wa èsín pé.

Ikú bàbá yèyé, Aláse èkejì Òrìsà, baba wa Aláàfin ti ilè Òyò, Oba Lamidi Adeyemi 111 se ayeye ojó ìbí rè ní òní tí won pé ogórin odún (80). Àrà méèrírí ni kábíèsí, Ikú bàbá yèyé nítorí baba ni wón ...

Read More »

Ikún je dòdò ikún n rédìí, Ikún kò mò pé ohun tí ó dùn a máa pa ni.Arábìnrin yí ni ó gba orí ìbùsún ya wèrè.

Ìròyìn jé kí á mò wípé arábìnrin yí ya wèrè léyìn tí eni tí ó ti láya nílé ba lájosepò tán. Gégé bí eni tí ó sún mo se so. Ó so wípé ó ti mo omobìnrin yí lára kí ...

Read More »

Isé kìí pa ni, ayò ní pa omo ènìyàn

Arábìnrin kan ni aso rè fàya ní enu ìdí látàrí àsejú rè nípa ijó tí ó fé kó mólè dáadáa, kí ó tún owó ijó náà mú láti ilè. Nínú fídíò tí a rí wò, tí a ti yo àwòrán ...

Read More »

Òkan lára Ilé ìgbé àwon akékòó ti Ilé-èkó gíga ifáfitì ti ìlú ilé-ifè tí a mò sí Obafemi Awolowo University gbiná lánàá.

Òkan lára ilé ìgbé àwon Akékòó ti ilé-èkó gíga ifafitì ti Obafemi Awolowo gbiná ní alé àná. Ilé ìgbé yìí a máa jé Alumni hostel, bí ó ti lè je wípé a kò fi tara tara mo bí ó se ...

Read More »

Bàbá Sàlá òrun rere re o. Gbajúgbajà elérí orí ìtàgé, tí gbogbo èèyàn mò sí bàbá Sàlá ti gba òrun lo ní àná ojó kesàn-án osù kèwà odún tí a wà yí.

Tí won bá ni èèyàn apanilérìn ni baba won kò paró rárá, nítorí àwon gangan ni oyè adérìn-ín-p’òsónú ye. Moses Olaiya Adejuwon (M.O.N), lórúko baba súgbón bàbá Sala ti gba orúko lówó won. Àsé kò sí eni tí kò ní ...

Read More »