Home / Àṣà Oòduà / È má jé kì olá èro ayélujára tàn yín je- báyìí ni Joke Silva wí.

È má jé kì olá èro ayélujára tàn yín je- báyìí ni Joke Silva wí.

Nínú ìfòròwánilénuwò nínú ìwé ìròyìn ti Genevieve Nnaji tí won se fún ognóntàrigì òsèré orí ìtàgé tí a mò sí Joke Silva, ni ó ti gba àwon èèyàn ní ìmòràn kí won má se jé kí ohun tí àwon elégbé òhun máa n pín sí orí ìtàgé tàn wón je, nítorí òpò nínú won ni ó ni nkan míràn tí won n se, yàtò sí eré orí ìtàgé nìkan.
Joke silva pín èrò rè ní orí èro ayélujára, ó ko síbè wípé
“E má se jé kí èro ayélujára tàn yín je. Òtító tó dájú ni wípé kìí se isé eré orí ìtàgé nìkan àwon tí e rí ni orí èro ayélujára ni n se, bíkòse wípé òpò ni ó ni nkan míràn tí won n se tí won fi n rí owó se ilé ayé won.òtítò tí ó wà níbè ni wípé, kò sí owó ní orílè èdè yí fún ilé ìsé wa atiwípé kò sí orò ajé ní orílè èdè Nìjíríà”.

About Awo

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo