Home / Àṣà Oòduà (page 173)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Alaafin of Oyo together with his Oloris welcome well-wishers at the palace

The Alaafin of Oyo, Oba Lamidi Olayiwola Adeyemi together with his four wives welcomed indigenes of the state who showed up to  felicitate with him on his recent birthday & other achievements at his Palace today. The Alaafin spoke and danced for his ...

Read More »

Kinni e ro pe o fa ijaa?

Kinni iwo ro pe o fa ijaa? a) Muri kan b) Owo olowo d) Ainitelorun

Read More »

Gbogbo ona loti baje !

O dabi ala loju mi ni, mo gbe ero alupupu ti mo sese ra lati ma gbe losi ayika ile Olorun, nitiripe gbogbo ona loti baje, moto ko rorun tabi ya lara lati gbe jade, mo gun ero alupupu naa ...

Read More »