Home / Àṣà Oòduà / Àwòrán láti ìlú olómìnira kan tí a mò sí Ewédú àti ìgbálè

Àwòrán láti ìlú olómìnira kan tí a mò sí Ewédú àti ìgbálè

Àwòrán láti owó omo oòduà rere.

Àwòrán láti ìlú olómìnira kan tí a mò sí Ewédú àti ìgbálè (a fé béè, èrín yakata).

Ta ló tún n’ìfé àwòrán láti ìjìnlè ìlú yorùba?

N’ísàlè ni àwòrán àjò lo sí ìlú Iseyin ní ìbèrè odún, mo se ìrántí kíka rè pé ilè wa kún fún wàrà àti eyin?…

About Lolade

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo