Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 53)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

Aseritu: Awon Agbofinro ‘SON’ Ri Ile Alaja Meji Ti Won Ko Ogun Ti O Ti Ba Je Si. (Aworan)

Awon  ‘SON’ (Standards Organisation of Nigeria) ti mu ogbeni akeruwole ti oun ta aye deru Kosimetik ati ọti-waini ti se ayipada awọn ogun ti ọjọ ti lo lori wọn ati ti o nri titun ọjọ lori wọn, ni eyi ti ...

Read More »

Ẹ̀rù ló sọ ọmọ Ẹkùn di Ológbò/Ológìní tó fi di ” Ẹran-àmúsìn – Ọdẹ peku-peku” –

Ni igbà àtijọ́, ẹranko ti wọn pè ni Ẹkùn jẹ alágbára ẹranko, bẹni Kìnìún si jẹ́ alágbára ẹranko. Bi Kìnìún ti lágbára tó ninú igbó, bi ó bá bú ramúramù, ohun gbogbo ninú igbó á pa kẹ́kẹ́ titi dé ori ...

Read More »

“Àṣejù Baba Àṣetẹ́” – Ìtàn bi Ojúkòkòrò àti Ìgbéraga ti jẹ́ Àṣejù

Ni ìgbà àtijọ́, ọkùnrin kan wa ti orúkọ rẹ njẹ́ Ìgbéraga. Wọ́n bi Ìgbéraga si ilé olórogún, àwọn ìyàwó bàbá́ rẹ yoku ni ó tọ nitori ìyá rẹ kú nigbati ó wà ni kékeré. Lẹhin ti o tiraka lati pari ...

Read More »

Obi ni nii Ofo !!

Obi ni bii Iku Obi ni bii Arun Obi ni nii Ofo Kolanut avert death Kolanut avert illness/disease Kolanut avert loss Obi(Kolanut) is sacred. He who bring Kolanut brings joy. Ase Ire O!!!

Read More »

Iwure: Odu Okanransode

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Abu ise ana o a si tun ki orire iwonu ose tuntun, ose yi yio san wa si ire gbogbo ako ni to ona iparun lose yi o ase. Laaro yi mo maa fi ...

Read More »

Igunuko !

Read More »

Orunmila Ni Olugbala Eda, Bee Naa Lo Si Tun Je Olugbala Fun Awon Irunmole Akegbe Re Naa

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Oni a san wa o, bi a se njade lo loni aanu eledumare koni fiwa sile o ase. Loni mofe ki e mo dajudaju wipe Orunmila ni olugbala eda, paapajulo awa adulawo bee naa ...

Read More »

E gbo oro Olodumare ninu odu mimo ti Orunmila,

E jiire eyin eeyan mi, e je ki a gbo oro Olodumare ninu odu mimo ti Orunmila, mo nki lati inu Ogbe ‘gunda (Ogbeyonu ), o ki bayi pe,’ Bibi inu ko da nkan, suuru ni baba Iwa, agba to ...

Read More »

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi?

Eku ise ana o, a si ku popo sinsin odun o emin wa yio se pupo loke erupe ninu alaafia ara o, bi a se njade lo loni eledumare ninu aanu re yio fi iso ati aabo re bowa lowo ...

Read More »

Ki Ni Oruko Eranko Yii

Read More »