Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 52)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

Àpẹrẹ Ìsìnkú Ìbílẹ̀ fún Arúgbó ni Ilẹ́ Yorùbá

Ìnáwó rẹpẹtẹ ni ìsìnkú arúgbó jẹ́ ni ilé Yorùbá.  Bi arúgbó bá kú ni ilé Yorùbá ki ṣe òkú ọ̀fọ̀ ṣùgbọ́n òkú ijọ àti ji jẹ, mi mu ni pàtàki bi irú arúgbó bá bi àwọn ọmọ ti ó ti ...

Read More »

Oríkì Àjọbí, Àṣà Yorùbá ti ó Nparẹ́ lọ

Oríkì* jẹ ọ̀rọ̀ ìwúrí ti Yorùbá ma nlò lati fi sọ ìtàn àṣà àti ìṣe ìdílé lati ìran dé ìran. Ninú oríkì ni a ti lè mọ ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ẹbí ẹni àti ohun ti a mọ ìdílé mọ́, bí i ...

Read More »

Olopa pa obirin kan ni ilu Eko

Olopa yinbon pa iyawo ile kan , ni adugbo kan ti aun pe ni Onipanu ni ilu Eko, nigba ti oun le ikan ninu awon omo ti won ma un fi ero ayelujara jale. Awon agbofinro so wipe won yi ...

Read More »

Orile ede, Russia, Iraq ati Syria, Fa oju ro si orile-ede Amerika.

Ijoba ile America ti se igbekale dosinni ti (Tomahawk) oko ohun ija ofurufu ni Siria, eyi ti awon kan ti oruko won un je (Pentagon) mo nipa re ni Ọjọbọ Ni ibamu si osise, (Washington) so wipe kemikali ija ikolu ...

Read More »

Ogbe Ni Alabo Kan yin ibon pa Orere Ni ilu Enugu

Oṣiṣẹ alabo kan ti orukore unje ogbeni Chidi Onyenekwu, padanu emi e lala iro tele, nipase asise ti ikan ninu awon ti won jo unsise abo se, Ni ibamu si Ọgbẹni Ugonna Chiji Achuko ti, afi oro wa nenu wo, ...

Read More »

Eniyan Kan Ku ni Mushin Narin Awon Omo Egbe Onijagidijagan

Rogbodiyan ti o be sile larin awon omo egbe onijagidijagan, Alamutu ati Alaka ni agbegbe kan ti a un pe ni Mushin ni ilu Eko eyi ti o fa ijamba ti o mu emi eniyan kan lo si orun aaremabo, ...

Read More »

Obinrin kò ṣe e jánípò si ìdí Àdìrò nikan, Obinrin ló ni gbogbo Ilé

Ìtàn fi yé wa wi pé Yorùbá ka ọ̀rọ̀ obinrin si ni àṣà Yorùbá bi ó ti ẹ jẹ wi pé obinrin ki jẹ Ọba nitori ni àṣà ilú, ọkunrin ló njẹ olóri. Obinrin kò pọ̀ ni ipò agbára. Àwọn ...

Read More »

Omo Egbe Yoruba ati ‘OPC’ (Oodu Peoples Congress) Fajuro lori rogbodiyan ti o sele ninu ile ife

Awon omo egbe apapo-Yorùbá-titi eka –oselu, Afenifere ati awọn omo egeb (Oodua Peoples Congress), OPC, ti fariga nipa rogbodiyan ti oun lo ni ilu Ile Ife. Ninu oro kan ti abenugo fun eggbe Afenifere kán so eyi ti un se ...

Read More »

Ti eba jabo si inu omi pelo ọkọ ayọkẹlẹ: Eleyi ni ona irọrun ti elefi gba emi yin la (Fidio)

Eleyi ni ona irọrun ti elefi gba emi yin la, ati ligba ti eba jabo si nu omi eyin ati ọkọ ayọkẹlẹ yin. A se iwadi wipe egbelegbe irinwo “400” awon eniyan ni ounku ni ododun lipa ijamba awon ati ...

Read More »

Eyin eniyan e wo E-moni(E-money) ninu photo titun re.

Alaga ti Ẹgbẹ eka marun apapo , wuni ninu poto re titun ti o sese ya.

Read More »