Home / Àṣà Oòduà / Ejowo O Eyin Ojogbon!! Efun Wa Ni Imoran Lori Ala Yi O

Ejowo O Eyin Ojogbon!! Efun Wa Ni Imoran Lori Ala Yi O

Aki gbogbo eyin ojogbon awo mimo lagbaiye ninu ILE NLA I.K.O. nla wayi o
Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA.)
Iye eni kokan wa koni ra ooo
Ejowo ooo
Ti obinrin basun tioba la ala wipe ohun pade were loju orun to nko enu ife si ohun ejowo too
Kin ni itumo ala bee ooo

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo