Home / Àṣà Oòduà / Aki Ijo Kinnihun Orunmila

Aki Ijo Kinnihun Orunmila

(Atorieni Tikosun wonSe)
TI ILU IBADAN LAPAPO OOO
Aki gbogbo ojogbon awo mimo lapapo lagbaiye ninu ile nla I.K.O. nla wayi oo
Wipe :- (KINNIHUN ORUNMILA O)
(ilosiwaju ishese lo jemi lo gun o)
Aki gbogbo apapo ojogbon awo mimo towa ninu ijo kinnihun orunmila ti ilu ibadan oo wipe
eku ipade ijo kinnihun orunmila ti.ile ibadan eleyi tiema se lojo ayajo jinmo tinse ojo eti
Apapo ojogbon awo mimo lapapo ni agbaiye won ni kiaki yin pupo wipe eku ipade ana oo
olodumare tofi ife koyin jo koni fi tu yin ka oo
iwaju iwaju ni ojugun gbe iwaju iwaju lema.lo oo
ekoni di ero eyin oo
ilu ibadan koni baje oo
ilu enikokan wa koni baje oo
ire gbogbo afi ile enikokan wa se ibujoko oo
Eku isee takun takun oo
Apapo ojogbon awo mimo lagbaiye wa pelu yin ooo

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo