Atete gbeni ju Orisa Ori atete niran Ori lokun Ori nide Ko si Orisa ti dani gbe leyin Ori eni Ori ni seni ta a fi dade owo Ori ni seni ta a fi tepa ileke woja Ori gbe mi ...
Read More »Those who have EBO as their weapon has it all.
Ebo doesn’t only solve problems, but Ebo get deep to the cause of the tribulation and solve it from the scratch. Ifa is still listening to prayers like old days. Orunmila still bless like he used to. Esu still accept ...
Read More »Se eyin tunle di ibo fun Arakunrin yi lekeji ?
Beni abi be ko?
Read More »Kini Oruko ogagun yi ?
Nje eyin ranti oruko oko yi
kini oruko oko yi ?
Read More »Foto: Egbo tani eni to joko yi
Tani eni to joko yi
Read More »Arewa Asa Toni: 17-04-2016 Ogbeni/Alaji Taiwo Hassan (Ogogo)
Arewa asa wa toni ni Alhaji Taiwo Hassan, abi won ni Ilaro ni odun 1959, baba tobi won ibeji ni, baba tobi baba won ibeji ni, emerin ototo ni won ti bi ibeji ninu ile won, Won losi ile-we alakobere ...
Read More »Iwure Owuro Toni: 17-04-2016
E MAA WI TELE MI : …… *Adun, ayo, idunnu ni temi titi aye *Ire owo, ire omo, ire aiku ni temi. *Apari inu mi ko ni ba tode mi je. *Orisun ayo mi ko ni gbe. *Ise mi ko ...
Read More »Odo Iwoyi !
A ki gbogbo wa ku ise oni, a si ki wa ku abo sori eto wa eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. E dakun e wa nkan fidi le abi ki e fi idi le nkan, ki a ...
Read More »Olobe Lo Loko Soko-Yokoto
Eto Olobe lo loko soko-yokoto ni o gori afefe bayii,,,,,, Adupe lowo olorun fun abo re lori wa, oba ti o pawa mo titi Di ojo oni, a dagbere ni ijejo, atun dupe wipe eledumare ka wa ye loni. Lori ...
Read More »
Àṣà Oòduà Àṣà Oòduà
