Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 73)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

Ounje Emi Fun T’ooro Yii (02-04-2016)

………………………………………………………. Iwe-Iroyin ‪#‎AYEKOOTO_MAGAZINE‬ fun T’osu kerin ti jade sita bayii, ‪#‎Ogorun‬ naira #100 ni beere fun tire lodo ‪#‎VENDOR‬ nibi-kibi …………………………………………………………… AMOYE TONII : ‪#‎ARABINRIN_FOLASHADE_TEMITOPE‬ ………………………………………………………….. …………………………………. HUN !!! ‪#‎Iya‬ to je omo f’ogun ‪#‎Odun‬ .. ‪#‎Osi‬ to ta omo ...

Read More »

Iwure Owuro 02-04-2016

E MAA WI TELE MI : ……. *Edumare ma je ki n soore daran. *Oluwa ma je ki n gbalejo oran. *Edumare ba mi segun elenini. *Oluwa ran alaanu si mi. *Edumare gba mi lowo alaroka. *Oluwa dakun rojo ibukun ...

Read More »

Edurona ibo la nba oro epo lo ni 9ja bai ooooo … ?

Elo leyin nra epo ladugbo yin????

Read More »

Idile Alayo: Oro owun si fe toju sumi

A ki gbogbo wa ku jimo oloyin toni a si ki wa ku abo sori eto Idile Alayo ti ose yi, gege bi ise wa atejise kan ti a ri gba lati owo okan lara won ololufe eto yi ni ...

Read More »

Àsodúnmódún ní í sawo àsodúnmódún..

Àsosùmósù ní í sawo àsosùmósù, Odún kì í dun ká má rìí ohun àjòdún. Olódùmarè á soore àrí tókasí fún ire láyé e eni iyì Oba Abel Simeon Olúwafémi bí e ti lé ódún kan lónìí. Àlékún owó, Àlékún ogbón, ...

Read More »

Iwure Owuro 27/03/2016

:::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::: E MAA WI TELE MI : ……… *Edumare ma fi omo pa mi lekun. *Oluwa ma fi mi pa omo mi lekun. *Ogun aye koni bori mi. *Iji aye koni ja lu mi. *Inira ati idaamu, koni je temi. ...

Read More »

Oruko wo won Npe Kini yi ni Ile Yin ?

?

Read More »

Ti o ba ni #500, osi fe da ina okele, Bawo Ni wa Sena ?

TI O BA NI #500 KOSI KEROSINE KOSI GARRI TABI ELUBO OSI FE DA INA OKELE BAWO NI WA SE NA #500 fi se okele ‪#‎antyfolashadealawada‬

Read More »

‪#‎Gbagede Asa-19/03/2016

Omo Oduduwa, Olodumare jogun awo to rewa fun wa; awo dudu ni gbogbo aye mo iran wa si, bo sie je wipe alawo pupa die naa nbe ninu-un wa. ……. Ewa n be lara awo dudu, nitori awa gan ni ...

Read More »

‪Laye Atijo: Opo Sisu (Nje o dara lati maa supo?)

Ni akoko, mo sure fun toko-taya pe iku aitojo ko ni pa gbogbo wa o(ASE EDUMARE). …….. Ni aye atijo, ti oko ba tete ku, ti iyawo re si tun wa loju-opon, won o ba so pe ki aburo oko ...

Read More »