Tag: Àṣà Yorùbá
-
Orewa kilode kilo fa ironu?
Bao ku ise o tan toripe yoruba bo won ni airise koni kapada si orun-alakeji tiko basi oko (farm) ao si ma re idale(travel) ko si eni to la laye yi tiko ni ri nkan wi, amo saa ti oro bari bayi, eledua lo ye ka ke pe pelu igbiyanju toripe die omokunrin ki to…
-
Fi ere si temi Eledumare
Ojulu! ojo nan re bi anan sugbon o ti pe odun kan bayi Eledua modupe, ibi ti ore nan de duro maje ko taku sibe o, fi ere si temi Eledumare, MAJE KIN KAABAMO BO TI WU KORI, orewa toripe o bami se amin O NI KAABAMO LORI IGBESE RE. oju- itere ojulowo omoYORUB Aatata
-
Orewa Abi Iwonan Ti Gbagbe Ile !
Orewa abi iwonan ti gbagbe ile, toripe eniyan to so ile nu ti so apo ‘ya ko, ajo ko dabi ile lo d’ifa fun agiliti to pada wa tun ile-baba re se, se ki se pe o ti gbagbe orirun re orewa? Ara-ile mi ko se eni eniyan mi kose eniyan ao ma gbodo fi…
-
Oba Erediauwa Ti Waja
Ojulu ooooo! iku ti pa abiri abiri ti rorun alakeji oooo! iku ti pa okan lara awon omo ODUDUWA Oba-Benin, gbogbo eyin ojulowo omoYORUBAatata e ku araferaku eni re OBA-EREDIAUWA ti ile-benin. bo ba de orun ko se orun re. sun reeooooo.
-
Awon osu ni ede Yoruba (12 Months of the Year in Yoruba Language)
E bami kaa si eti awon omo ni ile, January – seere February- Irele March – Erena April – Igbe May – Ebibi June -Okudu July – Agemo August – Ogun September -Owewe October – Owawa November – Beelu December -Ope.
-
YORÙBÁ DÙÚN KÀÁÁÁ
A – Alaafia ni fun o. B – Buburu kan ki yo o subu lu o. D – Dugbedugbe ibanuje ko ni ja le o l’ori. E – Ebi o ni pa o nibi ti odun yi ku si. E – Ekun, ose ko ni je tire. F – Funfun aye re ko ni d’ibaje.…
-
Ojuitere ooooooo!!
mo de werewere bi eji-ale mo de warawara bi ti iyaleta, ewe-itu lo ni ke tu mise ewe-iifa loni kefa mi mora, toripe enikan ki so okun mo igbin lorun, won ki fi pakute mu eja l’odo, beni omode koni si owo lu labelabe, toripe bi igbin ba su yo fi aya ko bi ijapa…
-
Eyin tia, e ku isinmi oni!
ARAYE KONI LU FUN WA JO, BATA-OFO, BATA- IBANUJE BATA-WAHALA won o ni bo si enu- onan gbogbo wa, gbogbo eniyan tiko ba yan Eledua l’odi e bami se ase, toripe INU- ALAGBAFO KI LE TITI KO BINU OMI. oju-itere ojulowo