Home / Àṣà Oòduà / Iwure Owuro Toni: 17-04-­2016

Iwure Owuro Toni: 17-04-­2016

E MAA WI TELE MI :
……
*Adun, ayo, idunnu ni temi titi aye
*Ire owo, ire omo, ire aiku ni temi.
*Apari inu mi ko ni ba tode mi je.
*Orisun ayo mi ko ni gbe.
*Ise mi ko ni dojuru.
*Eledua tete ran alaaanu si mi.
*Eledumare ma se fi atije mi sibi to nira(ASE).
…….
OLUWURE: Abileko Adeniyi Adesewa.

About ayangalu

2 comments

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo