Tag: Àṣà Yorùbá
-
GBEJÉÉ KIO NIYI
Éni Aye nyé loni, Kio dakun kio se araré jéjé, Éni Igba sii ndun fun, Kio jare Kio fi araré siwon. Ile-aye Kii se Awailo ilu rara. Olódùmarè Nikan ni aremabo. Ômô ti Abi Loni, ti osi di Éni A Njiké, Bose were, Adi éni Iku npa, Béé Sini ôpô Eniyan Atata, Ti Aye nyé, Ti…
-
ibere ranpe daruko awon nkan meji yi ati wipe awon wo ni won nlo ?
jowo fi idahun re sowo si mi ti o ba je ojulowo omo yoruba
-
Oro Sunuku
Moki gbogbo wa ku ise oni, asejere ni gbogbo wa yoo se lagbara Eledua ase. Eyi ni lati fi to gbogbo a wa ololufe eto yii leti wipe, gbakogbi itan akakogbon ti a npo po ti di itan agbeleka fun gbogbo wa lati ola lo. ……..Akole itan naa ni. ORE MI, mo wa ngba ladura fun…
-
Oro Sunku: Ore Mi, Iran Keji
-Sola:. ( O wole, o kumle si egbe ibusun Baba ati Iya re) E jowo, mo nilo owo nile eko ni. Won fun wa ni ise asatilewa kan ni, yoo si na mi to egberun marun naira. -Baba Sola:. Ha! Egberun marun ke? -Sola:. Bee ni, baami. Mo ti tu egberun meji jo ninu re…
-
Oro Sunku: Ore Mi, Iran Kerin
(Ni nnkan bi aago meje irole ni ibugbe awon obinrin ni ogba Yunifasiti, ero po nibe lokunrin lobinrin. Awon kan n wole, awon kan n jade. Awon okunrin miiran wa ninu oko ayokele pelu awon omoge, won n soro. Awon miiran tile n diro sibi to sokunkun, won nlo mo ara won. Aago merin ni…
-
Omidan asewo ti se ‘kerewa’ koja sorun alakeji
Awon Yooba bo, won ni owo tada mo ni kada lehin. Iku ogun ni i pa akikanju, omi ni pada wa pa omuwe lodo. Okan ninu awon omo asewo ilu Abuja ti oruko re n je Omidan Ome Enyi lo ti se agbako iku ojiji bayii lenu ise nabi to yan laayo. Omobirin eni odun…