Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 74)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

Iwure Owuro – 18/03/2016

E MAA WI TELE MI : …… *Sekere kii rode ibanuje, oro ibanuje koni je temi. *Tijo-tayo ni ti sekere, oro ayo ati idunnu ko ni tan ninu ile mi. *Ogun idile ko ni bori mi. *Ki osu yii to ...

Read More »

Emi Ibinu

Oruko mi ni IBINU, emi ko le fun wara, sugbon mo le da wara nu. Ise ti eniyan ba fi ogun odun ko jo, emi IBINU le fi iseju kan baaje. Sora fun emi IBINU ti o ba fe se ...

Read More »

Oro Sunuku – Ore Mi, Iran Kefa .

.( Ni gbongan adulawo ni Yunifasiti Afonja, awon eniyan n wole leni tere, eji tere. Won n gba tikeeti, won si n wole jokoo. Awon ti o fe safihan sinima naa n gunke, won nso. Won nfa waya, won gbaradi. ...

Read More »

Iwure Owuro – 14.03.­2016

*Edumare ma fi omo pa mi lekun. *Oluwa ma fi mi pa omo mi lekun. *Ile alayo mi ko ni di ile ibanuje *Ogun aye ko ni bori mi. *Iji aye ko ni ja lu mi. *Ayo mi ko ni ...

Read More »

Owe Toni: Pari owe yi

1.Awolu mate e????? 2.Enitio dasofun ni??????

Read More »

GBEJÉÉ KIO NIYI

Éni Aye nyé loni, Kio dakun kio se araré jéjé, Éni Igba sii ndun fun, Kio jare Kio fi araré siwon. Ile-aye Kii se Awailo ilu rara. Olódùmarè Nikan ni aremabo. Ômô ti Abi Loni, ti osi di Éni A Njiké, ...

Read More »

ibere ranpe daruko awon nkan meji yi ati wipe awon wo ni won nlo ?

jowo fi idahun re sowo si mi ti o ba je ojulowo omo yoruba

Read More »

Biodun Okeowo lori eto Gbajumo Osere

Read More »

Ara lori eto Gbajumo Osere

Read More »

Nje toba jepe Eyin Ni arakunrin yi

Kilerope Elese Fun Iru nusi bayi ?

Read More »