Home / Àṣà Oòduà / GBEJÉÉ KIO NIYI

GBEJÉÉ KIO NIYI

Éni Aye nyé loni, Kio dakun kio se araré jéjé, Éni Igba sii ndun fun, Kio jare Kio fi araré siwon. Ile-aye Kii se Awailo ilu rara. Olódùmarè Nikan ni aremabo. Ômô ti Abi Loni, ti osi di Éni A Njiké, Bose were, Adi éni Iku npa, Béé Sini ôpô Eniyan Atata, Ti Aye nyé, Ti éda si nfé, Bopé titi won A déni Iku Nmulô. Ko Sohun towa Tii kii tan Laye.  Afi ôla Olódùmarè nii Ntoni jé.Bi oni Irinwo Éru loni ti o ko Gbejéé, Bi o sini GbinGbin nikin-ôrô ti o ko se wô ô. B’ose were, Won a sanlô bi éyé. Éni toti niri, Awadi éni Nraago kiri. Se Éyé lôla, Éyé sini Igbi-ôrô. Bi oni won Dakun Mase Gberaga.

Gbejéé kio niyi ôré mi. Nitori pe, Igba Agbejéé kii fô kia, Béé Sini Awo Agbejéé kii faya Bôrô-Bôrô.Sugbon Eniyan tio fi Wadu-Wadu ko Aye m’aya, ti ko Gbejéé, Bopé titi, Adi éni Aye Nté kiri, Yôyô Lénu Aye, Yôyô lénu Eniyan. Éni To npôn é loni, Tio yô titi, Bose were, A buô lola bi Éni la’yin. Se Ôgbôgbô Iyawo Nbô wa Dôtun-ba nté, Gbejéé o Niyi Ôré mi, Aye Nipa, Aye Nipôn.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo