Tag: Àṣà Yorùbá
-
Femi Adebayo, Funke Akindele, Mercy Aigbe, Toyin Aimakhu nibi ami eye Africa Magiki 2016
Aimoye osere lo peju sibi ami eye (Africa Magic Viewers Choice Awards) 2016 to waye niluu Eko. Eyi to waye yii ni i se elekerin iru e. Oruko awon olubori ami eye naa wa nisale .
-
Owo Jegudujera Abacha: Ile ejo ti fesun kan Obasanjo ati Jonathan
*Won tun ranse si Yar’Adua lode orun wi pe ko wa salaye *Ile ejo ti gbe ise to le fun Aare Buhari lati se Obasanjo, Yar’dua ati Jonathan Kootu ijoba apapo to gaju lo to kale siluu Eko, Federal High Court, ti fesun kan awon aare ti won ti n je lati odun 1999 ti…
-
Iyanu ti sele nipa awon omo Babington Ikorodu ti won jigbe
Ni ojo Aje to koja yii (29/02/15) ni awon ajinigbe kan yawo ileewe Babington Macaulay Junior Seminary School to kale si agbegbe Ikorodu nipinle Eko ti won si ji awon omo obirin akekoo meta salo raurau. Gege bi alaye ti oga agba ileewe naa, Ven Olaoluwa Adeyemi, se, o ni koto giriwo kan ni awon…
-
Rogbodiyan Mile 12: “Won ja omo ikoko gba lowo mi” – Abiyamo
Leyin rogbodiyan to be sile ni agbegbe Mile 12 to wa niluu Eko l’Ojobo ose to koja yii (03/03/16), okunrin kan ti oruko re n je Daniel Igba lo ti ke gbajari sita wi pe, awon kan ja omo gba lowo oun nigba ti wahala naa gbena kari. Ninu itaporogan to waye laaarin eya awon Hausa…
-
Omo odun metadinlogun (17) joba nile Naijiria
*Isele naa farape ti Awujale tile Ijebu Oba Sikiru Adetona, Awujale tile Ijebu, eni ti won bi lojo kewaa osu karun-un odun 1934 gori ite awon baba re lojo keji osu kerin odun 1960 leni odun merindinlogbon (26), eleyii ti n se eni ojo ori re kere julo lati joba nile Yoruba. Nibayii, Obi Chukwuka…
-
Jegudujera: EFCC tun ti gbe ebi Alison-Madueke niluu Abuja
Awon Yooba bo, won ni tina ko ba tan laso, eje ki i tan leekanna. Awon ajo ti n gbogun ti iwa jegudujera ati sise owo ilu mokunmokun, EFCC, ti gbe arakunrin Donald Chidi Amamgbo to je okan lara ebi arabirin Diezani Alison-Madueke lori esun gbigbon epo robi ile wa lona aito. Arakunrin Amamgbo ni…
-
Awon igbimo Olubadan foju Seriki gbole ni kootu
*Won ti dajo iwuye Adetunji gege bi Olubadan tuntun Gege bi oro awon Yoruba to wi pe, ti oba kan ko ba ku, oba mi ki i je. Eleyii ni awon igbimo Olubadan tile Ibadan tele pelu bi won se da ojo tuntun ti won yoo fi oba tuntun je leyin ipapoda Oba Samuel Odulana…
-
“Efon ti n fa kokoro Zika wa ni Naijiria, kosi ti gboogun”- Minisita Ilera
Minisita fun eto ilera, Ojogbon Isaac Adewole, ti se idaniloju alaye wi pe, efon abami ti n sokunfa kokoro Zika ti ko gboogun ti wa ni Naijiria. Bakan naa lo si ro awon eniyan lati se ohun gbogbo ni ikapa won lati dena efon lati ma fenu kan won lara. O ni awon eniyan le…
-
Bayii ni a se le se iwosan fun eni to ni kokoro inu eje
Awon ohun elo ti a gbodo wa ni yii: 1 Omi osan wewe igo kan tabi oti igo kan tabi omi grape igo kan 2 Capsule red & yellow eyo mewaa (10 pieces) 3 Ewe taba ti won ti lo, sibi imuko kan pere Bi a se le pese ogun naa ni yii:…