Tag: Àṣà Yorùbá
-
Ewu to wa ninu foonu lilo ati pataki ilera wa
Opolopo wa ni a n lo foonu ni aye ode oni, sugbon ti a kosi mo awon ewu keekeke to ro mo o eleyii to le se ipalara fun ago ara wa. E je ka ri daju wi pe a n nu foonu wa lorekoore. Paapaa julo, ti a ba lo foonu wa ni akoko…
-
Iwosan ogbe inu
Awon nnkan won yii lo maa n se okunfa ogbe inu; ki eniyan maa fi ebi pa ara re nigba gbogbo, jije ounje gbigbona ati iyo pupo ninu ounje ati bee bee lo. Bi a se maa se iwosan naa ni yii: A ma wa ogede agbagba dudu ti ko ti pon meje (7). Leyin…
-
E jowo eyin, abiyamo, e dakun e gba wa ni imoran ..
OOOOOOO Oro naa ti di lbanuje ati edun okan fun molebi mi, e dakun e gba mi ooooo. Mo je Omo odun metadinlogbon (27 years) Taiwo. . . . . . ni Oruko mi, Okunrin ni mi, bakan naa ni ekeji mi naa n je Kehinde, Obinrin nii . . . . ., Omo ipinle…
-
Sisi ologe elo ni Suru ooo
Se Eledumare to da IDI yin bi o se mon IDI kaluku yin se ko se da ni in? Awon kan wa sese ma lo ogun abi abere. Se ni tori iranu yi na E wo won oooo. Awon kan ni IDI won ti baje yi ooooo Latara pe won tu ise Eledumare wo. Ko…
-
Eyin ojogbon eniyan, kini itumo awon oro won yii ?
Enikan lo lo ki ore re,ko si ba ore re nile, sugbon o ba okan ninu awon omo ore re nile. Oni baba re n ko? Omo naa ni:”Baba mi lo so okun (rope) aye ti o fe ja” Iya re naa n ko? Omo naa ni:”Iya mi wa ni ese kan aye ese kan…
-
Eku Dede Asiko Yi Ni Gbogbo Ibi Ta A’Ba Wa o
Oruko mi ni TINUKE mofe ki eyin omo ilu yi gbami ni yanju lori oro yi ni ooooo Lati bi osu marun se yin ni ago ibani soro kan man pe mi Ti eni yen ba pe mi EPE nla Loman se funmi. Ti moba pe pada EPE na tun ni in. Ana ojo isinmi…