Home / Author Archives: BalogunAdesina

Author Archives: BalogunAdesina

Sisi ologe elo ni Suru ooo

Se Eledumare to da IDI yin bi o se mon IDI kaluku yin se ko se da ni in? Awon kan wa sese ma lo ogun abi abere. Se ni tori iranu yi na E wo won oooo. Awon kan ...

Read More »

Onka ede Yoruba 100 – 20,000

Orisun  Onka ede Yoruba 100-Ọgọrun 110- Adọfa, àádọ́fà 120- Ọgọfa 130- Aadoje 140- Ogoje 150- Adọjọ, àádọ́jọ 160-Ọgọjọ 170-Adọsan, àádọ́sán 180- Ọgọsan 190-Mẹwadinigba 200-Igba E tesiwaju ni isale lẹhin iwe Bireki yii (Continue after the page break bellow)

Read More »

E wo ohun ti Funke Akindele n se lowo?

Funke Akindele ti pada si ni sere idaraya eleyii to n se lati din ara sisan re ku. Awon obirin onise tiata maa n se eleyii lati mu ara awon wa ni ipo odo, eleyii to se pataki si irufe ...

Read More »

Aye ye Rotimi Amaechi ninu Abuja

Aimoye ero wa pade Rotimi Ameachi nikete to jade ninu ile igbimo asofin Abuja lonii.   Foto Rotimi Amaechi ati iyawo re leyin to yege niwaju ile igbimo asofin agba gege bi minisita ti won yan

Read More »

E wa wo bobo to fi tattoo ya Davido si aya re

Davido pada pade bobo to fi tattoo ya aworan omo baba olowo si igbaaya re. Ebun ti Davido fun naa ni alakorun ti won fi goolu se. O si so fun bobo naa wi pe awon ti di abi kan ...

Read More »

IFA NI KASOPE, KASOPE

IFA NI KASOPE, KASOPE MO NI KASOPE KASOPE IFA NI KOMO EKU O SOPE OMO EKU LOHUN LOPE DA IYAN LOMO ARAYE NFI OMO EKU JE IFA NI KASOPE KASOPE MO NI KASOPE KASOPE IFA NI KOMO ERAN O SOPE ...

Read More »

Opon Ifa !

Read More »