Tag: Àṣà Yorùbá
-
Ohun to pada sele si maanu to lo gbadun ara re nile asewo buru jai
Maanu yii lo lo gbadun ara re nile asewo kan niluu Benin. Aisanwo leyin igbadun lo di ohun ti won da igbati jo fun un.
-
Senato ipinle Ekiti pin iresi fun awon eniyan bi Fayos
Awon eniyan ti won gbe ni agbegbe ekun Guusu Ekiti gbajo tilu tifon nigba ti arabirin Biodun Olujimi ti n soju won nile igbimo asofin agba Abuja si obitibiti ounje wolu l’Ojobo ose to koja yii. Apo iresi, ororo ati aimoye awon nnkan ti enu n je ni Senato Olujimi ko wa lati da awon…
-
“Awon irinse ti a n lo ti darugbo”- Oga panapana ilu Eko
Oga agba ileese panapana ti ijoba apapo, Federal Fire Service, eka ti ipinle Eko, Ogbeni Aderemi Olusola Theophilus ti sapejuwe ikiyesara gege bi ogun-ajisa lati dena ijamba ina abaadi. Ninu oro re, eleyii to so lori telifisan ipinle Eko, o ni ona to ya ju lati yago fun ijamba ina ni ki awon eniyan sora…
-
Aye awon asewo nile awon omo yahoo-yahoo
Bi yahoo-yahoo ni won ni abi ogun oloro ni won gbe, ta lo mo. Sugbon o daju wi pe, eni to n sise gege bi omoluabi ko ni da iru eleyii lasa wo laelae. Ori ayelujara ni aworan yii ti bere si ni fonkiri, eleyii to n se afihan awon asewo ti won jo mojumo, ti…
-
Obirin kan bi omo sinu Keke Maruwa
Onise ara ni Olorun oba. Omobirin alaboyun kan lo bere si ni robi ninu Keke Maruwa ni akoko ti won gbe lo si ile iwosan lati lo bimo niluu Enugun. Eyi to ju ibe ni wi pe, ojo odun lo tun wa bosi(1/1/16))nirole patapata. Awon osise ile iwosan alabode ti won fe gbe lo gan-an…
-
Won ti fi Ladoja je Osi Olubadan
Won ti fi Senator Rashidi Adewolu Ladoja je Osi Olubadan lonii (01/01/16) ni aafin Oba Samuel Odulana Odugade, Olubadan tile Ibadan.
-
E pade awon ore yin nibi
Orisiirisii ona ati idi pataki ni awon eniyan fi n yan ore tuntun. Awon kan fe alajoso, awon kan fe alabaro, awon kan si n fe eni ti won yoo jo maa takuroso lasan. Eyiowu ko je, ore dun ti a ba fi ife otito ati ododo ba ara wa lopo. Die lara awon ti…
-
Kini ero yin nipa awon obirin to ga fiofio?
Mo mo wi pe awon obirin maa n fe lati fe awon okunrin to ba ga. Sugbon mi o mo boya bakan naa lori pelu awon okunrin nipa fiferan awon obirin to ga fiofio. Se kii se wi pe giga obirin le mu awon okunrin maa sa fun?