Tag: Àṣà Yorùbá
-
Kini ijoba n se nipa awon ti n se ayederu?
Orisun iwe Iroyin Iroyin yii kii se tuntun, yoo si ti to bi osu kan o le die ti asiri awon to n se ayederu elerindodo Coca Cola ti jade. Sugbon iru awon iroyin bayii, a kan maa n gbo naa ni. To ba ya, ategun yoo fe koja lori won, a ko si ni…
-
Idi pataki meta ti ko fi ye ka maa fi ehin je eekanna
1. Ehin le yingin tabi ki die kan lara ehin wa: Nigba mi-in ti a ba n gbiyanju lati fi ehin ge eekanna wa, ehin wa le lura won lojiji, eleyii si le fa ki ehin yingin legbe kan tabi ki die lara re kan danu. 2. Erigi enu wa ninu ewu: Bakan naa, fifi…
-
Tinuola Oyindamola pegede!
Oni ni ojo-ibi Omidan Tinuola Oyindamola, okan ninu awon ti won karoyin wa lojoojumo. Adura wa ni wi pe ke e dagba ninu ogbon, ola ati alaafia.
-
Ofin mokanla to le mu awo ara dabi omo tuntun jojolo
Orisun 1 E yee sa ara yin sinu oorun koja bo ti ye lo. Paapa julo, e sora fun awon oorun lati bi ago mewaa aaro si ago meji osan. Orisii oorun yii a maa mu ki awo eniyan o sa. 2. E ri wi pe e n se imototo awo ara yin nigba gbogbo.…
-
Dele Momodu se afihan Madueke nigba keji
Fun awon ti ko mo, Dele Momodu ni oniroyin akoko to koko se afihan foto Diezani Alison-Madueke. Eleyii to ya nigba to se abewo si minisita fun epo robi nigba kan ri ni ilu London.Oga Dele Momodu ti pada se afihan Madueke leekansii. Ekunrere iroyin nipa obirin naa kosi ni pe jade ninu iwe iroyin…
-
“Iyawo mi n yale, o tun bimo ale fun mi”: Alabi yari ni kootu Ikorodu
Orisun Ogbeni Alabi Rasheed, eni odun mejidinlaadota (48) ti gbe iyawo re, Sherifat, lo si ile ejo lati tu yigi igbeyawo odun mewaa to wa laaarin won ka lOjobo ose to koja yii. Gege bi alaye Alabi ni Ikorodu Customary Court to kale siluu Eko, oko Sherifat salaye fun ile ejo wi pe ayewo…
-
Saraki gba Basketmouth lalejo niluu Abuja
Aare ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki, gba Basketmouth lalejo ninu ile re to wa niluu Abuja
-
Awon akekoo LASU yari, won ni awon alase n ko leta si yanponyanrin
Lati Ọwọ Olayemi Olatilewa Awon omo egbe akekoo Ifafiti tilu Eko, Lagos State University Students Union (LASUSU) ti bere si ni fariga pelu ifehonuhan latari bi awon alase ileewe naa se fi owo kun owo igbaniwole awon akekoo tuntun. Ifehonuhan naa lo buruke lojo Isegun to koja yii nigba ti awon akekoo ni ki awon…
-
“Idagbasoke awon akonimoogba gbodo je koko fun NFF” – Amodu
Shuaibu Amodu, okan lara awon igbimo oludari ajo NFF ti so wi pe ona kan pataki lati se igbelaruge fun ere boolu alafesegba abele ni nipa sise eto idagbasoke fun awon akonimoogba ere boolu ile Naijiria. Oro yii ni Amodu, eni odun metadinlogota (57) se niluu Minna nigba ti won pate idanileko ita gban-angba fun…