Tag: Àṣà Yorùbá
-
Won gun pasito ijo RCCG lobe niluu Ota
Edward Campbell, eni odun mokandinlaadota (49) ni won ti gbe lo si ile ejo lojo Eti to koja yii pelu esun wi pe o gun pasito Redeemed Christian Church of God (RCCG), Dotun Olojede, lo be. Ile ejo Majisireeti to gaju lo to wa l’Ota nipinle Ogun ni asoju ileese olopaa, Sajenti Chudu Gbesi ti…
-
Otun Olubadan tile Ibadan ti dagbere faye
Otun Olubadan ti ile Ibadan, to tun je okan pataki ninu awon agba oye ile Ibadan, Omowale Kuye, ti dagbere faye leni odun metadinlaadorun (87). Oloye yii la gbo wi pe o dake ninu ile re to wa ni agbegbe Ikolaba to wa niluu Ibadan ni nnkan bi ago meje abo ale Ojobo ose to koja…
-
E wo ohun ti won fi ibeji da lara
Nje e le biliifu eleyii? Awon ibeji okunrin meji fe awon ibeji obirin kan naa. Awon pasito meji to so won po, ibeji ni won. Awon ore iyawo meji to tele won, ibeji ni won. Awon omo iyawo obirin, ibeji ni won. Awon omo iyawo okunrin, ibeji ni awon naa. Ilu India ni igbeyawo naa…
-
Arun oju: Ohun ti e o se ti oju ba n su tabi yun yin
Ti oju ba yun eniyan, tabi ti oju naa ba n su. Olayemi Oniroyin ti lo sewadii nipa ona ti eniyan fi le setoju iru oju bee lona to rorun ju lo. Ti eni naa yoo si bo ninu wahala arun oju patapata. Bi a se le se itoju iru oju naa ni yii: Oyin…
-
Mercy Aigbe alaso oge pade Toke Makinwa
Awon Yoruba bo, won ni tode-tode ni i se alaso tuntun. Joojumo ni Mercy n sodun, Mercy Aigbe alaso oge. Mercy tun pade Toke, sorosoro ori redio ati telifisan ti oun naa feran oge lagbo ariya.
-
Dayo Amusa ti pada senu ise
Dayo Amusa wa lara awon ero Mecca odun yii pelu awon akegbe re bi Fathia Balogun ni won jo goke arafa papo. Igba ti won de ni won di Alaaja tuntun. Sugbon bayii, Dayo ti pade sidi ise oojo re nibi won ti n dana fiimu tuntun.
-
Eleleture lati owo Akeem Lasisi
Eyi ni fidio orin ewi lati owo Akeem Lasisi ti won pe akole re ni ELELETURE
-
Somi Edumare lati owo Edaoto
Odun lo sopin, eni Edua Oke pamo nikan lo yege. Sugbon nipa temi ati awon ololufe mi, a ko ni padanu enikeni lase Eledumare. Ase Lori eyi ni i ti ma fi yin sile lati je igbadun orin Edaoto to pe ni Somi Edumare.
-
Ika eniyan wo lo yo oju Ibrahim sa lo?
Okunrin olokada kan ti won pe oruko re ni Ibrahim ni won sadeede ba oku re loju titi laaaro yii ni agbegbe Alaba Suru to wa loju ona masose Badagry niluu Eko. Igba ti won yoo ye okunrin naa wo, won ri wi pe won ti yo oju re sa lo.