Tag: Àṣà Yorùbá
-
Dayo Amusa n dan bi egbin
Dayo Amusa rode ariya lonii ojo Satide. Omobirin naa si se afihan foto re ko to jade kuro nile. Ka ma paro, Alhaja yii fine gan-an.
-
Odun Thaipuisam: Irin sonso ni awon eniyan fi n gun ara won niluu India
Odun Thaipuisam je orisii odun kan ti awon elesin Hindu ti won gbe ni Guusu apa orileede ile India ma n se. Ninu odun yii ni awon eniyan ti maa fi irin sonso orisiirisii gun ara won ni gbogbo ara. Igbagbo won ni wi pe, bi inira won ba se po to nipa fifi irin…
-
E wa wo ohun ti omo Naijiria kan an se lori afara
Mo ri okunrin aro kan ti ko lapa kan lori afara ti awon elese n gba soda niluu Eko. Okunrin naa n fi igbale gba gbogbo ori afara laise wi pe enikeni gbese naa fun. Isesi okunrin naa wu mi lori, mo si sun moo lati foro wa lenu wo. ori re ko daru, eniyan…
-
Awon foto ayeye isinku Mama HID Awolowo
Eyi ni die lara awon foto to jade nibi eye ikeyin ti won se fun Mama HID Awolowo eni ti won pada sin lojo karunlelogun osu kokanla odun yii, 25/11/15. E tesiwaju lati wo awon foto to ku.
-
Egbe APC Kogi ti yan oludije gomina tuntun
Leyin gbogbo rukerudo oselu to ti n sele nipinle Kogi, eleyii to bere leyin iku Abubakar Audu, awon egbe APC ti yan Yahaya Bello gege bi eni ti yoo ropo Audu to ku. Ogbeni James Faleke naa si ni won fe lo gege bi igbakeji re. Sugbon titi di akoko yii, a ko le ti…
-
E ba wa dasi oro yii: Ninu ipo ati iya eni, e wo lo gaju?
Leyin ti won fi Sanusi je Emir tilu Kano, oba. Ilu Kano si gba wi pe oosa ajiki bi iya ko si laye. Eleyii lo mu gomina banki agba ile yii nigba kan ri teriba niwaju yeye to bi i lomo. Nje asa Yoruba tewogba iru ohun ti Sanusi se yii? Nje Ooni tuntun le…
-
Eto idibo gomina ipinle Kogi di fopomoyo
*Faleke n binu, ara ilu n sofo *Iwe ofin ruju mo awon amofin loju *Won tun ni kan fomo Audu je gomina apapandodo Leyin iku Abubakar Audu, oludije fun ipo gomina labe egbe oselu APC nipinle Kogi, eni to jade laye nikete ti ajo INEC kede wi pe eto idibo gomina to waye nipinle naa…
-
Yemi Osinbajo: Ori taa fi sewe
Igbakeji Aare, Yemi Osinbajo nigba to wa nile iwe alakobere Corona School, Lagos. Awon Yoruba bo, won ni ori taa fi sewe kii kuro lorun eni taa ba dagbalagba.
-
E wa wo ohun ti oludije ipo gomina n se lagbala pelu aya re.
Eng Seyi Makinde, okan ninu awon oludije ipo gomina nipinle Oyo, labe egbe oselu SDP ninu eto idibo odun 2015 to waye ni yii pelu aya re. Gege bi iwadii Olayemi Oniroyin lati enu awon to sun mo eni ti awon kan tun mo si Omi Tuntun. Won fi ye Olayemi Oniroyin wi pe, maanu…