Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 86)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

Awon Obirin to n binu si oludari CRIN niluu Ibadan bora sile nihoho

Awon Obirin to n binu si oludari CRIN niluu Ibadan bora sile nihoho Olayemi Olatilewa Gbegede gbina niluu Ibadan lojo Monde to koja yii nigba ti awon osise ibudo imo ti won ti n sewadii ijinle nipa koko, Cocoa Research ...

Read More »

Atelewo ni mo bala

Ki n to so die fun yin lara itan igbesi aye mi kan ti mi o le gbagbe laelae. Se e ko gbagbe alaye ti mo se fun yin lose to koja? Lara ona ti eniyan le fi se se ...

Read More »

“Ise aye lo mu mi fadi omo odun meji ya”- Okunrin eni aadota odun (50) lo so bee

“Ise aye lo mu mi fadi omo odun meji ya”- Okunrin eni aadota odun (50) lo so bee Olayemi OlatilewaOkon Michael, eni aadota odun (50) to fi tipatipa fadi omobrin eni odun meji (2) ya perepere ni ipinle Akwa Ibom ...

Read More »

Enikan ti Buhari gbagbe lati fun ni ipo misita

Ohun ti Ogbeni Yanju Adegboyega ko nipa maanu naa ni yii: “Walaaahi! Mo sese gbagbo loooto ni pe, alaimoore lo po julo ninu awon oloselu. Olorun n gbo, alaimoore ni Aare Buhari ati egbe oselu APC. Eyin o gbagbo? O ...

Read More »

Okiki fi Oore Ofe gbe Femi Solar jade: Fidio orin tuntun yii leku!

Femi omo Oladele ti gbobo eniyan mo si Femi Solar ti fi gbogbo awon ololufe re lokan bale pelu fidio orin re tuntun to pe ni GRACE nigba to n fi die ninu fidio naa to won lenu won. Gege ...

Read More »

O se o Eledua ! Alaafia ti n pada sara Oliseh

Akonimoogba egbe agbaboolu Super Eagles, Sunday Oliseh, si wa ni ile iwosan niluu Belgium nibi to ti n gba itoju lowo. Iroyin tuntun to te Olayemi Oniroyin lowo lati enu awon dokita isegun oyinbo ti n toju re fi ye ...

Read More »

Oko ajagbe jale moto kekere lori ni Pota

Ijamba oko yii lo waye lale oni ni masose ilu Port Harcourt si Aba. Oko ajagbe kan lo yi le mo kekere kan lori eleyii ti eniyan wa ninu re.

Read More »

Omidan to n wa ore tuntun fi leta ati Foto re ranse

Omidan Toyin lo kowe si wa wi pe oun fe ore, ko so wi pe oun wa oko o. Awon ore tuntun lo n fe, eni ti won yoo jo maa takuroso lasan. Awon to ba nife sii le fi ...

Read More »

Leta ife jade lojo ti Olamide Orente se ojo-ibi alarinrin

Eni odun ba ba laye, e pe ko sope. Eni Edua oke ba dasi, e pe ko ke aleluya s’Olorun Oba.  Ojo nla ni ojo oni je, ojo kejila osu kokanlan odun, ojo ti Omidan Awelewa Amoke, Oba Oge Eleyinju-ege ...

Read More »

Gobe Sele Nigba Ti Omo Yari Wi Pe Oun o ni fohin

Yorùbá Dùn shared the following link and had this to say about it: Oloorun ni omo naa, ko fe ki won ba fohin re lero ni won ba mu lele fun un. Nje ohun to buru wa ninu igbese ti ...

Read More »