Home / Tag Archives: ewi

Tag Archives: ewi

Ewi Toni: Egbe APC iba oooo

Egbe ofo Toko coronal wo Nigeria Egbe abamo ti ki tele ofin. Akuse egbe tin pin rice agolo Kan fun eniyan mewa

Read More »

Ewi Toni – 09-04-2016

Bisu eni ba ta Ka fowo booje lo to Agba ofifo ni dun koro koro Mo ti reru to domo Mo si ti riwonfa to ko peteesi Igba o lo bi orere Owo aago laye To ba lowaju a tun ...

Read More »

Ewi Toni: Atoto arere

Gbogbo omo Yoruba Ki gbogbo eye igbo pa lolo Etu to n numo lowo O ma lee numo Gbogbo Ekulu ko ma lee numo loka Omo Ade ti de to fe korin ogbon Akewi Imoran de to fe farofo sasaro ...

Read More »