Tag: governor of lagos

  • Èmi ò kì ń s̩e “His Excellency” – Sanwo-olu

    Ogbeni Babajide Sanwo-olu ni mi. Mi o ki n n se “His excellency”.
    Gomina ipinle Eko lo n salaye yii fun awon oniroyin lonii ojo kefa osu kokanla odun yii.
    Gomina ni igberaga wa ninu oruko ” His Excellency “. E saa maa pe emi ni “Mr Governor “.
    Gomina ni iwe iso-di-ooto re gan-an maa jade ni ola, ojo keje, osu ti a wa ninu re yii.